Oba ft. DWise Lyrics
- Genre:Gospel
- Year of Release:2017
Lyrics
Olorun Oba aja majebi (Idinma)
Ire logbeja oniyan koniyan maja mo (Idinma)
Olorun Oba Alewilese (Idinma)
Ire lo seleri kileri maye o (Idinma)
Olorun Oba Asoromatase (Idinma)
Ire lo soro oniyan koniyan ma soro mo (Idinma)
Ba mi soro
Eseni re le biro
Laye lorun
Eseni re le biro
Ina ale emafi we tosan
Ina wole okunkun a pamo
Olorun loba laye atorun
Dada oniyan
E wole fun o
Oba ni
Olorun Oba aja majebi (Idinma)
Ire logbeja oniyan koniyan maja mo (Idinma)
Olorun Oba Alewilese (Idinma)
Ire lo seleri kileri maye o (Idinma)
Olorun Oba Asoromatase (Idinma)
Ire lo soro oniyan koniyan ma soro mo (Idinma)
Ina njo
Igbe kojo
Ba mi Olorun lomo
Afefe fe
Igi wole fun
Eh Ba mi Olorun lomo
Omoga nit’iroko igi
Arugbo ojo Eledumare
Oba ni
Olorun Oba aja majebi (Idinma)
Ire logbeja oniyan koniyan maja mo (Idinma)
Olorun Oba Alewilese (Idinma)
Ire lo seleri kileri maye o (Idinma)
Olorun Oba Asoromatase (Idinma)
Ire lo soro oniyan koniyan ma soro mo (Idinma)
Baba Ese gan o Eledumare
Daddy Ese gan o Awimayehun
Ipokipo timo ba wa
Ma yin Eledua
Ipokipo timo ba wa
Ma yin Eledua
Eda toni ko s’Olorun nile aye
Orisa ti oto Eledumare ni yo masin
Eda toni ko s’Olorun nile aye
Orisa ti oto Eledumare ni yo masin
Baba loke o twale o
Baba Atobiju mo juba Re iba o