Omo Baba Lyrics
- Genre:Gospel
- Year of Release:2017
Lyrics
Iba Olorun (Iba Edumare) 2x
Iba Jesu Baba mi
Bomode ri Jesu **
Okunkun ri Jesu ofo danudanu
Oya o ejeka juba Oluwa
Iba Olorun (Iba Edumare) 2x
Iba Jesu Baba mi
Bomode ri Jesu **
Okunkun ri Jesu ofo danudanu
Oya o ejeka juba Oluwa
Omo Baba lemi
***
Awon agbagba merinlelogun
Ti mbe la jule orun
Wonma yin Jesu Baba mi
Mowa gbegba ope
Mele lu kangbe
Ebere bami je
Mo wan jijo ope
Mele lu kanjo
Ebere bami jo 2x
Iba Olorun (Iba Edumare) 2x
Iba Jesu Baba mi
Bomode ri Jesu **
Okunkun ri Jesu ofo danudanu
Oya o ejeka juba Oluwa
(Iba Edumare)
Iba Olorun (Iba Edumare)
Iba Jesu Baba mi
Bomode ri Jesu **
Okunkun ri Jesu ofo danudanu
Oya o ejeka juba Oluwa
Sikasika koma yale mi 4x
Sikasika toba yale mi asan ku
Sikasika toba yale mi adete
Peganpegan toba yale mi asan ku
Peganpegan toba yale mi adete
Mujemuje toba yale mi asan ku
Mujemuje toba yale mi adete
Ani sikasika toba yale mi asan ku
Sikasika toba yale mi adete
Peganpegan toba yale mi asan ku
Peganpegan toba yale mi adete
Sikasika koma yale mi 2x
Ani mujemuje toba yale mi asan ku
Mujemuje toba yale mi adete
(Iba Edumare) 2x
Iba Jesu Baba mi
Bomode ri Jesu **
Okunkun ri Jesu ofo danudanu
Oya o ejeka juba Oluwa
Iba Olorun (Iba Edumare) 2x
Iba Jesu Baba mi
Bomode ri Jesu **
Okunkun ri Jesu ofo danudanu
Oya o ejeka juba Oluwa