Mio Gbokankan (Remix) ft. Qdot Lyrics
- Genre:World Music/Folklore
- Year of Release:2022
Lyrics
Mio Gbokankan (Remix) (Remix) ft. Qdot - Destiny Boy
...
Lyrics by
IG:khall_me_rockystar
mo dabi buhari, wo ti getimilo mio gbo kan kan
mo ti trabaye, colorado lo gbe mi looo
Awon temi dami mo,
somori dami mo,
Agege dami mo,
ikorodu dami mo
toba rimi ni igboro, omo mi alagbe,
omomo moriamo ni,
ajeh ko tie gbo kan kan
Emi kan jaye mi (mio gbo kan kan)
Mio ri kan kan (mio gbo kan kan)
Mo fe buga won (mio gbo kan kan)
Paso ma tungba won (mio gbo kan kan)
Ema koba mhi (mio gbo kan kan)
Oro owo lobami (mio gbo kan kan)
Ti bati rowo (mio gbo kan kan)
inumi ama dun (mio gbo kan kan)
wo ni no she yahoo (mio gbo kan kan)
mo ra oko balu (mio gbo kan kan)
moshe party pa malu (mio gbo kan kan)
won wa binu mi (mio gbo kan kan)
Aba iya yin (mio gbo kan kan)
aba baba yin (mio gbo kan kan)
afako pa yi (mio gbo kan kan)
ma fi owo mi buga yin (mio gbo kan kan)
Lowo yi (mio gbo kan kan)
Oro owo ni mo gbo oo (mio gbo kan kan)
Ti mo ti gba waya (mio gbo kan kan)
Credit card (mio gbo kan kan)
wo ti ge eti mi (mio gbo kan kan)
ma yo ju simi (mio gbo kan kan)
oya kala won (mio gbo kan kan)
moni ko buga won (mio gbo kan kan)
owo te fi gba ile (mio gbo kan kan)
lawa fin gba apate (mio gbo kan kan)
daya loru (mio gbo kan kan)
Rolex lowo(mio gbo kan kan)
Fendi lomo wo (mio gbo kan kan)
Dior lomo Jo (mio gbo kan kan)
I dey enter dubai (mio gbo kan kan)
kenya wo southy (mio gbo kan kan)
ota mi ti darun (mio gbo kan kan)
selling wo panti (mio gbo kan kan)
owo Inu ora(mio gbo kan kan)
owo inu shaka (mio gbo kan kan)
owo to po leti (mio gbo kan kan)
to wuwo lowo (mio gbo kan kan)
toba rimi ni gbo ro (mio gbo kan kan)
omo mhi destiny (mio gbo kan kan)
ko gbo kan kan (mio gbo kan kan)
ko ti e gbo kan kan (mio gbo kan kan)
gbo mi si gbo mi si
ko to
opa tinri kan ile okon oru
ojo
kilo ba oba jeun layi salamo
eshin shin
ewu ke be ebe ke ku
e bin tin
Alhaji awa (mio gbo kan kan)
IBD dende (mio gbo kan kan)
MC oluomo (mio gbo kan kan)
presidential Labuwabe (mio gbo kan kan)
sam larry ti settle e (mio gbo kan kan)
badi osha (mio gbo kan kan)
SP general (mio gbo kan kan)
data sly (mio gbo kan kan)
60:40 bilique (mio gbo kan kan)
kogbagidi (mio gbo kan kan)
climax travel ( mio gbo kan kan)
sakuti (mio gbo kan kan)
Ibro king (mio gbo kan kan)
easy money (mio gbo kan kan)
ugly goat (mio gbo kan kan)
makinde 9ja loaded (mio gbo kan kan)
olowo eji gbo (mio gbo kan kan)
big team (mio gbo kan kan)
bi bi re (mio gbo kan kan)
surest nationa (mio gbo kan kan)
kekere motor (mio gbo kan kan)
ko gbo kan kan
2t upon the poco