Emi Lo N'Soni Di Alaye Lyrics
- Genre:Gospel
- Year of Release:2017
Lyrics
[ti:03 Emi Lo N'Soni Di Alaye]
Emi lon soni di aye
Ara koma ni ere mo
Emi olorun lo n’soni di alaye
Eran ara koma ni ere mo
Emi lon soni di aye
Ara koma ni ere mo
Emi olorun lo n’soni di alaye
Eran ara koma ni ere mo
Emi lon soni di aye
Ara kikida asan
Erupe yipada di erupe
Ara koma ni ere mo
Emi lon soni di aye
Ara koma ni ere mo
Emi olorun lo n’soni di alaye
Eran ara koma ni ere mo
Emi lon soni di aye
Ara erupe lasan lasan
Emi olorun lon soni d’alaye
Ara koma ni ere mo
Emi lon soni di aye
Ara koma ni ere mo
Emi olorun lo n’soni di alaye
Eran ara koma ni ere mo
Kini omo eniyan
Asan
Kini omo eniyan
Asan ni
Kini omo eniyan
Asan
Kini omo eniyan
Asan ni
Omo eniyan koma lola ju eranko
Iku ton pa aguntan ton pe ewure
Iku kono lon pani
Se eri aye o abi eko ri
Seri aye o tabi eko ri
Won waye moya
Won se ara loto fun ikan je
Oniwasu ori keji ise ikerin sowipe
Mose ise o la fun ara mi
Mo ko ile pupo
Agbala iyara nla
Oniruru igi eleso
Omo odo lokunrin lobinrin
Agbo malu ati aguntan
Moko fadaka jo fun ara mi
Isura ti enikankan ko ni ri
Sugbon kiyesi o asan ni gbogbo re patapata
Imule mofo kosi ere Kankan labe orun o
Kini omo eniyan
Asan
Kini omo eniyan
Asan ni
Kini omo eniyan
Asan
Kini omo eniyan
Asan ni
Omo eniyan koma lola ju eranko
Iku ton pa aguntan ton pe ewure
Iku kono lon pani
Se eri aye o abi eko ri
Seri aye o tabi eko ri
Won waye moya
Won se ara loto fun ikan je
Afi omo eniyan we koriko oo
Koriko igbe
Af’omo eniyan we koriko
Koriko igbe
Af’omo eniyan we koriko
Koriko igbe
Af’omo eniyan we koriko
Koriko igbe
Toba dowuro ko to re a tan mini mini
Sugbon lale o ododo re a re danu
Af’omo eniyan we koriko
Koriko igbe
Af’omo eniyan we koriko
Koriko igbe
Af’omo eniyan we koriko
Koriko igbe
Sisha loun laye
Boti wu ko lewa to kosi dan to
Sisha loun aye
Oun alayilayole logo re
Sisha loun laye
Boti wu ko lewa to kosi dan to
Sisha loun aye
Oun alayilayole logo re
Ewo omo eniyan to dara tosi wun ni
Bo wun ni nigba akoko toba dogbo o adi sisha
Gbogbo ewa re ton wun ni asi ro
Nitori pe oun aye yi akonise layi ni baje
Paradise nikan lo le wa layi di ibaje o
Ilu ayo
Paradise nikan lo le wa layi di ibaje o
Ilu ayo
Paradise nikan lo le wa layi di ibaje o
Ilu ayo
Paradise nikan lo le wa layi di ibaje o
Ilu ayo
An ke
An so
An ke
An so
Ati gbagbe pe oja laye je
Ki lan gbe mi
Ki lan nje tan webe saya
Ojo melo la o lo laye tan gbewo erin wo
Alagemo ton rin jeje iku pa
Opo lon jon ara re mole
Ki lan gbe gbin o laye
Eje a ranti ile o ka gbeje mimo
Won shori dudu jen bawon pe jo
Won kora jo po jen bawon de ibe
Shebi ka sha ti bawon pe jo nile isin ni
Ara oju be lo
Ati wiwiwi e leyin o ni gbo
Ati fofofo e leyin o ni gba
Awa olorin nko pasito ko sinmi
Toba se pe ko mo wa mo
Nitori ati so fun o iwo ni ko gba
Akoni nijo ki fun ni lese ijo
Rara rara rara rara rara
Akoni nijo ki fun ni lese ijo
Rara rara rara rara rara
Toba ti wipe jo bayi jo bayi
A ko gba sile
Ati fono igbala yi han o o
Eyi toba fe se ni
Toba se pe ko mo wa mo
Nitori ati so fun o iwo ni ko gba
An ke
An so
An ke
An so
Nibo o
Nibo ni o wa
Nibo o
Nibo ni o wa
Boju wo waju
Boju weyin
Boju wo osi
Wo apa otun
Omo leyin jesu ronu jinle
Lati ipinle ese aye re wa
A a legbe o lori osuwon ki o tun pe
Nibo ni o wa
Nibo o
Nibo ni o wa
Nibo o
Nibo ni o wa
Oko fun oko re alapase ko tan o
Awon kan tun wa ninu ogba won so le lenu se
Egbe buburu lon ba iwa rere je
Egbe buburu lon ba iwa rere je
Eje mi mo
Eje mi mo
Eje mimo ni iwe mimo wi
Eje mi mo
Eje mi mo
Ge beni to peyin ti je mi mo
Egbe buburu lon ba iwa rere je
Egbe buburu lon ba iwa rere je
Ema se ba alagbere kegbe
Ema se ba onija kegbe
Irera ija ki o doun atijo
Eya yin soto pata ni ireti pe tempili olorun le je
Ema se ba olomuti kegbe
Ema se ba elegbe okunkun kegbe
Iwa omuti ki o dohun ati jo
Eya yin soto pata ni ireti pe tempili olorun le je
Egbe buburu lon ba iwa rere je
Egbe buburu lon ba iwa rere je
Eje mimo
Eje mimo
Eje mimo ni iwe mimo wi
Eje mi mo
Eje mi mo
Ge beni to peyin ti je mimo
Eje mimo
Eje mimo
Eje mimo ni iwe mimo wi
Eje mi mo
Eje mi mo
Ge beni to peyin ti je mimo
Ge beni to peyin ti je mimo
Ge beni to peyin ti je mimo
Ge beni to peyin ti je mimo