Daddy Daada (High Praise) Lyrics
- Genre:Gospel
- Year of Release:2017
Lyrics
[ti:01 Daddy Daada (High Praise)]
Moni daddy kan
E bami yin daddy mi
Moni daddy kan
E bami yin daddy mi
Moni daddy kan
E bami yin daddy mi
Oun lo da aye
E bami yin daddy mi
Oun lo da orun
E bami yin daddy mi
Eja inu ibu
E bami yin daddy mi
Eye oju orun
E bami yin daddy mi
Ope lo fi rori
E bami yin daddy mi
Iyin lo fi bora
E bami yin daddy mi
Gbogbo agbaye
E bami yin daddy mi
Oya ka yin daddy
E bami yin daddy mi
Ko fimi sere
E bami yin daddy mi
Daddy dada
Daddy dada
Daddy dada
Daddy dada
Timba le gbe o soke
Nba fi eh han faraye
Kole mo jesu ni baba
Daddy dada
Daddy dada
Moni daddy kan ye
Moni daddy kan o
Moni daddy kan ye
Moni daddy kan o
Moni daddy kan ye
Moni daddy kan o
Olowo ori mi oko mi
Moni daddy kan o
Alagbawi mi baba mi
Moni daddy kan o
Arugbo ojo olorun mi
Moni daddy kan o
Moni daddy kan ye
Moni daddy kan o
Moni daddy
Moni daddy
Moni daddy
Moni daddy
Daddy rere
Daddy dada
Daddy rere
Daddy dada (x2)
Daddy dada
Daddy dada
Daddy dada
Daddy dada
Timba le gbe o soke
Nba fi eh han faraye
Kole mo jesu ni baba
Daddy dada
Daddy dada
Amara chineke
Amara chineke
Amara chineke
Amara chineke
Eze chineke idimma
Eze chineke idimma
Eze chineke idimma
Eze chineke idimma
Amara chi
Amara zo
Eze chineke idimma
Chineke na zigi ka
Eze chineke idimma
Chineke ka odimma o
Eze chineke idimma
Nagode yesu
Seriki
Nagode yesu
Seriki
Ayiki yesu
Seriki
Ayiki baba
Seriki
Yowa yesu
Seriki
Yowa baba
Seriki
Yowa yesu
Seriki
Yowa yesu
Seriki
Nagode
Seriki
Nagode
Seriki
Nagode som som som
Seriki
Seriki
Seriki
Mode mowa fiyin fun o daddy
Mode baba
Mode mowa fiyin fun o baba
Mode baba
Bi mo ba legberun ahan
Mode baba
Koto lati yin o daddy
Mode baba
Bi irun ori mi je kkiki da ahan
Mode baba
Koto lati yin o daddy
Mode baba
Apata nla eleruniyin
Mode baba
Oro nla tin gbe oro mi o
Mode baba
Aterere kari aye ja
Mode baba
Awimayehun baba mi o
Mode baba
Apata nla eleruniyin
Mode baba
Mode mode mode
Moti de
Mode baba
Mo mope wa mo mu yin wa o
Mode baba
Ounje ti e fe ni mo gbe wa
Mode baba
Ope ati iyin lounje re o
Mode baba
Oba to dami loun adura
Mode baba
Folashade fope fun o baba
Mode baba
Wa mase dake woran did eyin oluwa
Oluwa awon oluwa
Oba awon oba
Gbongbo idile jesse
Kiniun eya Judea
Fun ore re lori ra
Lori oko
Lori omo
Lori aya
Ati gbogbo ile re o
Eyin oluwa
Gbogbo eniyan
Mofi ope ati iyin fun oluwa
Mofi ope ati iyin fun oluwa
Oba toni gbogbo ipa
Toni gbogbo agbara
Ti agbara re kari gbogbo aye
Mofi ope ati iyin fun oluwa
Mofi ope ati iyin fun oluwa
Mofi ope ati iyin fun oluwa
Oba toni gbogbo ipa
Toni gbogbo agbara
Ti agbara re kari gbogbo aye
Mofi ope ati iyin fun oluwa
Oba to gun iji leshin
Ope nla ni mo mu wa fun oba nla to ga
A gbo ma sa
A gbo ma ti
Erujeje jeje leti okun pupa
Oba nla ninu aye nla
Oba to lo korin kese
Mimo mimo to takete sibi tie se ko le de
Okunrin wa
Okunrin wo
Okunrin wawa wowo
Okurn rin gbonyi gbonyi gbonyi loju ogun ni
Arogun ma sa
Arogun ma so ojo
Alugbangba loju ogun
Ogbeja
Ogbeja keru o bo nija
Ato gbangba sun loye
Eni kerin ninu ino ileru
Ojiji firi
Eni ko o mo
Eni mo o ko
Bembe oju ono
Oyi biri biri biri pojo iku da
Akobi ninu awon oku
Togbe iku mi layi rarun o
Gbengbeleku to dako lenu emi mimo
Awo gbogbo arun ma gbe eje
Oba to dangajia
Oyigi yigi yigi yigi awuwo mase gbe
Olubori aja bori loju ogun
Oba to ran oro re to mumi lara da
Odi nigbekun o fun mi leru rere
Mofi ope ati iyin fun oluwa
Mofi ope ati iyin fun oluwa
Mofi ope ati iyin fun oluwa
Oba toni gbogbo ipa
Toni gbogbo agbara
Ti agbara re kari gbogbo aye
Mofi ope ati iyin fun oluwa
Gbogbo obinrin aye e dide yin oluwa
Oba to mu obinrin loun to ni o bi omo jade
O pasa fun iroro ibe ko dohun igbagbe o
Mofi ope ati iyin fun oluwa
Mofi ope ati iyin fun oluwa
Mofi ope ati iyin fun oluwa
Oba toni gbogbo ipa
Toni gbogbo agbara
Ti agbara re kari gbogbo aye
Mofi ope ati iyin fun oluwa
Oba to so ori buruku di ire
To bu ewa kun eru
O gbe talaka dide lati ori atan
Pelu omo alade jeun
Mofi ope ati iyin fun oluwa
Mofi ope ati iyin fun oluwa
Mofi ope ati iyin fun oluwa
Oba toni gbogbo ipa
Toni gbogbo agbara
Ti agbara re kari gbogbo aye
Mofi ope ati iyin fun oluwa
Wa o
Wa o
Wa o
Gbo o
Ore gbo o
Moyo mo l’oluwa lono kono
Bami gb’oluwa ga
Wa o
Wa o
Wa o
Gbo o
Ore gbo o
Moyo mo l’oluwa lono kono
Bami gb’oluwa ga
Nigba kan ri kosi ayo lay emi
Nigba kan mo biwa ninu ese
Sugbon o de pleu igbala to peyi
O pe mi wale sagbo igbala
Ore wa gba jesu ko ri ire laye re
Wa o
Wa o
Wa o
Gbo o
Ore gbo o
Moyo mo l’oluwa lono kono
Bami gb’oluwa ga
Abanise l’olorun mi o
Oba ti kin gba abetele eku ise
Abanise l’olorun mi o
Oba ti kin gbowo gbobi baba eseun seun seun
Abanise l’olorun mi o
Oba ti kin gba abetele eku ise
Abanise l’olorun mi o
Oba ti kin gba abetele eku ise
Abanise ma l’olorun mi
Oba ti kin gba abetele mo gbe o ga
Abanise l’olorun mi o
Oba ti kin gba abetele eku ise
Abanise l’olorun mi o
Oba ti kin gba abetele eku ise
Abanise l’olorun mi o
Oba ti kin gba abetele eku ise
Emi mimo komi bi mase yin o
Oba olokiki ma leyi o
Emi mimo komi bi mase yin o
Oba olokiki yi o ya mi lenu
Emi mimo mo nilo ise re o ninu aye mi
Wa komi bi un o t ma yin olorun
Emi mimo komi bi mase yin o
Oba olokiki ma leyi o
Emi mimo komi bi mase yin o
Oba olokiki yi o ya mi lenu
Emi mimo komi bi mase yin o
Oba olokiki ma leyi o
Emi mimo komi bi mase yin o
Oba olokiki yi o ya mi lenu
Mo tin roba ijoye pupo
Sugbon iru jesu Kristi kosi o
Mo tin roba ijoye pupo
Sugbon iru jesu Kristi o showon yeye
Emi mimo komi bi mase yin o
Oba olokiki ma leyi o
Emi mimo komi bi mase yin o
Oba olokiki yi o ya mi lenu
Okiki jesu yi kan o gba ile gbogbo o
Okiki jesu yi ma kan o gba ile gbogbo
Okiki jesu yi kan o gba ile gbono
Okiki jesu yi ma kan o gba ile gbogbo
Okiki jesu yi kan o o kari aye
Okiki jesu yi ma kan o gba ile gbogbo
Okiki jesu yi kan o sise iyanu
Okiki jesu yi ma kan o gba ile gbogbo
Modi ro oruko jesu yi o o mu ayanmo se
Okiki jesu yi ma kan o gba ile gbogbo
E pe oloruko ton je
Olokiki iyanu iyanu iyanu
Olokiki iyanu(x3)
Moni ibi o ban lo wun o ba lo o olorun mi
Ibi o ban lo ni wun o ba o lo
Ibi o ban lo ni wun o ba o lo
Alabarin mi laye o
Ibi o ban lo ni wun o ba o lo
Ibi o ban lo ni wun o ba o lo
Ibi o ban lo ni wun o ba o lo
Alabarin mi laye o
Ibi o ban lo ni wun o ba o lo
Oba to ga lori oun gbogbo
A joran jo ran ninu awon orun
Oke kanka ribiti leyin olododo
Adano fino ya
Adano fino fon
Aru gagagagagagagaga ino o
Oloruko nla baba mi ni
Omi mile mile bi igi oko
Ariro ala
Ologo didan ologo ayiku
Olorun awon omo ogun
E sope ibi o ba gbe un yio ma gbe
Ibi o ba gbe un yio ma gbe
Ibi o ba gbe un yio ma gbe
Ibi o ba gbe un yio ma gbe
Ibi o ba rin un yio ma rin
Ibi o ba rin un yio ma rin
Oun tio fe ma ba o fe
Oun tio fe ma ba o fe
Oun to wun o ni yio wun mi
Oun to wun o ni yio wun mi
Un yio ba o dele dandan
Un yio ba o dele dandan
Un yio ba o dele dandan
Un yio ba o dele dandan
Oloruko nla nla
Oloruko nla nla
Oloruko nla nla
Oloruko nla nla
Oloruko to tobi
Oloruko to tobi
Seri bo se kale aye ja
Seri bo se kale aye ja
O te ile bi eni teni
O te ile bi eni teni
O te orun bi eni te aso
O te orun bi eni te aso
Ofi ile-aye se apoti itise
Ofi ile-aye se apoti itise
O se oun gbogbo loju loju o
O se oun gbogbo loju loju o
O ga tobi o ju ogbon ori lo
O ga tobi o ju ogbon ori lo
Afuye genge mase gbe
Afuye genge mase gbe
Afuye genge mase gbe
Afuye genge mase gbe
Jingbini jingbini bi ate ileke
Jingbini jingbini bi ate ileke
Oba mi ni oba re ni
Oba mi ni oba re ni
Moni oba mi ni oba re ni
Oba mi ni oba re ni
Eje ka yin o
Ma gbe ga
E yin o
Ma gbe ga
E yin o
Ma gbe ga
Eje ka yin o
Ma gbe ga
Olori aye
Ma gbe ga
Eleru niyi
Ma gbe ga
Omode yin o
Ma gbe ga
Agba yin o
Ma gbe ga
Okunrin yin o
Ma gbe ga
Obinrin yin o
Ma gbe ga
Arugbo yin o
Ma gbe ga
Ikoko yin o
Ma gbe ga
Moyin jesu logo
Moyin jesu logo
Baye ti fe ko ri o beko lo ri fun mi
Moyin jesu logo
Moyin jesu logo
Moyin jesu logo
Baye ti fe ko ri o beko lo ri fun mi
Moyin jesu logo
Talo sope olorun o lagbara
Baba orun se kisa
Talo sope olorun o lagbara
Baba orun se kisa
Kilo se
O se eni
O se meji
O se meta
O se merin
O se marun
O se mefa
O se gudugudu meje
O tun se uncountable
Baba orun se kisa
Larin ewu aye lo mu mi rin to pami mo
Ojiji iye apa re mofi bora
Larin ewu aye lo mu mi rin to pami mo
Ojiji iye apa re mofi bora
Larin ewu aye lo mu mi rin to pami mo
Ojiji iye apa re mofi bora
Ojiji iye apa re
Mofi bora
Ojiji iye owo otun re
Mofi bora
Inu ogbon ibi re
Mofi bora
Ojiji owo otun re
Mofi bora
Ojiji ino ile re
Mofi bora
Hallelujah
Hallelujah
Hallelujah
Hallelujah
Moyin jesu
Moyin jesu
Moyin jesu titi aye
Hallelujah
Hallelujah
Hallelujah
Hallelujah
Moyin jesu
Moyin jesu
Moyin jesu titi aye
Hallelujah
Hallelujah
Hallelujah
Hallelujah
Je ka gbe ga
Je ka yin yi
Je ka gbe ga
Je ka yin baba
Hallelujah
Hallelujah
Hallelujah
Hallelujah
Moyin jesu
Moyin jesu
Moyin jesu titi aye
Agbara ti paro owo ninu aye mi
Kosi oun koun t’esu le se ninu aye mi
Agbara ti paro owo ninu aye mi
Kosi oun koun t’esu le se ninu aye mi
Ko soun t’esu lese
Ko soun t’esu lese
Ko soun t’esu lese
Ko soun t’esu lese
Ko soun t’esu lese
Agbara ti paro owo ninu aye mi
Agbara ti paro owo ninu aye mi
Kosi oun koun t’esu le se ninu aye mi
Agbara ti paro owo ninu aye mi
Agbara ti paro owo ninu ise mi
Agbara ti paro owo ninu ile mi
Agbara ti paro owo laye gbogbo wa
Oro oluwa wipe ibi ti sura omo eyan ba wa
Nibe gangan okan re yio ma wa
Moti ko eyin sura mi jo sile ologo
Moti ko eyin sura mi jo sile ologo
O daju pe mi yio layo lojo ti mo ba dele
Moti ko eyin sura mi jo sile ologo
Moti ko eyin sura mi jo sile ologo
O daju pe mi yio layo lojo ti mo ba dele
Moti ko eyin sura mi jo sile olorun
Moti ko eyin sura mi jo sile ologo
O daju pe mi yio layo lojo ti mo ba dele
Moti ko eyin sura mi jo sile ologo
Moti ko eyin sura mi jo sile ologo
O daju pe mi yio layo lojo ti mo ba dele
Isura wan be nibe
On be nibe
Ade ogo be nibe
On be nibe o daju
On be nibe o
On be nibe o daju
Oruko wan be nibe
On be nibe o daju
O daju pe a o layo lojo ti a ba dele
Moti ko eyin sura mi jo sile ologo
Moti ko eyin sura mi jo sile ologo
O daju pe mi yio layo lojo ti mo ba dele
Gbadura fun alafia nigeria
Gbadura fun alafia nigeria
Awa to fe nigeria yio a o se rere
Gbadura fun alafia nigeria
Gbadura fun alafia nigeria
Awa to fe nigeria yio a o se rere
Okunkun to su bole biri yio di imole
Igba otun yio pada wa de o lase baba
Gbadura fun alafia nigeria
Gbadura fun alafia nigeria
Awa to fe nigeria yio a o se rere
Jeki ibi onise ibi ko dawo duro
Eki ise ika won wa sopin baba
Jeki ibi onise ibi ko dawo duro
Eki ise ika won wa sopin baba
Jeki ibi onise ibi ko dawo duro
Eki ise ika won wa sopin baba
Jeki ibi onise ibi ko dawo duro
Eki ise ika won wa sopin baba
Oba mi ti kin le ni koto gbani mu
Jowo bami mu awon ota so lodo re baba
Jeki ibi onise ibi ko dawo duro
Eki ise ika won wa sopin baba
Oku naboti le ja fun lojo ojosi
Aye temi ni ke ja fun o olorun baba
Jeki ibi onise ibi ko dawo duro
Eki ise ika won wa sopin baba
O dara fun mi o
Tori jesu gbenu mi
O dara fun mi o
Tori jesu gbenu mi
O dara fun mi o
Tori jesu gbenu mi
O dara fun mi o
Tori jesu gbenu mi
Bi mo sun yio dara
Bi mo ji o yio dara
Mon jade yio dara
Mon wole o yio dara
O dara fun mi o
Tori jesu gbenu mi
O dara fun mi o
Tori jesu gbenu mi
O dara fun mi o
Tori jesu gbenu mi
E sope baba dara
Baba dara
E sope baba dara
Baba dara
E sope baba dara o
Baba dara
E sope baba dara o
Baba dara
E sope baba dara o
Baba dara
E wipe baba dara
Baba dara
Ise mi o ninu aye o jesu
Je ko le re lodo re o baba
Ise mi o ninu aye o jesu
Je ko le re lodo re o baba
Ise mi o ninu aye o jesu
Je ko le re lodo re o baba
Ise mi o ninu aye o jesu
Je ko le re lodo re o baba
Fi ere si ise mi baba
Fi ere si ise mi baba
Fi ere si ise mi baba
Fi ere si ise mi baba
Ki ise mi ma dise onise
Fi ere si ise mi baba
Ki ise mi ma dise onise
Fi ere si ise mi baba
Kowo mi ma dowo olowo
Fi ere si ise mi baba
Kile mi ma dile onile
Fi ere si ise mi baba
Komo mi ma domo olomo
Fi ere si ise mi baba
Komo mi ma domo olomo
Fi ere si ise mi baba
Kaye mi ma di aye alaye
Fi ere si ise mi baba
Ki ere mi ma di ele rere
Fi ere si ise mi baba
Fi ere si ise mi baba
Fi ere si ise mi baba