Osuba (Call to prayer) Lyrics
- Genre:Gospel
- Year of Release:2022
Lyrics
Osuba (Call to prayer) - THETIMO
...
Ah ah ah ah ah ah
Osuba re re
Osuba re re o o
Osuba re re o o
Osuba re re o o
Olori aiye
Oba to laiye
Olori orun
Oba to l'orun
You are the sounding of the waters
You're the droplets of the rain
Mo juba re, f'oribale
All creations speak Your glory
Sky, the deep, the firmament
Won juba fun
Oba to d'ohun gbogbo
Osuba re re o
Ah ah ah ah ah
Osuba re re o
Ah ah ah ah ah
Osuba re re o
Ah ah ah ah ah
Osuba re re o
Ah ah ah ah ah
Bi a ba s'eni l'oore, ope la nda o
Oba mi alagbala nla
Eti kan agbogbo aiye
Olugbo orun ti ngbo t'iye t'omo
Gb'oteranko, gbo t'eye, gbo t'eja inu odo
Baba am'oyun igbin nínú ikarawun
Om'akuko 'diye nínú eyin
Am'ofun m'edo
El'eti gborogbodo oro ki'ikun
Abeti lu k'ara k'ara, lu k'ara, lu k'ara bi ajere
Baba mi ti ngbo adura
Ehhhheh
Ti mba ti nbere, Oun se temi
Oba to nje mi, ni gb'eje gb'ejo
Ti mba ti nbere, Oun se temi
Oba to nje mi, ni gb'eje gb'ejo
Ti mba ti nbere, Oun se temi
Oba to nje mi, ni gb'eje gb'ejo
Ti mba ti nbere, Oun jemi ni O
Ti mba ti nbere, Oun se temi
Oba to nje mi, ni gb'esan gb'ewa o
Oba to nje mi, ni gb'eje gb'ejo
Ti mba ti nbere, l'oruko Jesu
Ti mba ti nbere, Oun se temi
O o oh
Oba to nje mi, ni gb'eje gb'ejo