![Sise (Work)](https://source.boomplaymusic.com/group10/M00/05/01/74309fe5175f4617a39ff760048d2549_464_464.jpg)
Sise (Work) Lyrics
- Genre:Folk
- Year of Release:2022
Lyrics
Pa ranran
Isé loògùn ìsé (Work is the way out of poverty)
Isé loògùn ìsé (Work is the antidote for poverty)
Isé loògùn ìsé
Sisé
Isé loògùn ìsé
Isé loògùn ìsé
Isé loògùn ìsé
Sisé
Sisé Sisé jare ìsé
Sisé Sisé s'oga ole
Eni ari t'ogb'oju logun
Ofi 'rare f'osi tani
Baba re le l'owó l'ówó, k'iya re l'esin leekan
B'ogboju le won peren, o te tan, o te tan
There's dignity in labour
Dignity brings favour
F'ako si
F'ikaramo si
Live your fantasy
Add some extra to your work
Something extra, e go pay
Extra work is extra pay
Soon enough, your hustle go pay
Isé loògùn ìsé
Isé loògùn ìsé
Isé loògùn ìsé
Sisé
Isé loògùn ìsé
Isé loògùn ìsé
Isé loògùn ìsé
Sisé
Te'pa mo'se (Work smart)
Te'ra mo'se (Work hard)
Ore e mi (Dear friend)
Life is full of competition
Frenemies write petition
Never want your liberation
War against your emancipation
Oju orun t'eye e fo oh
Inu ibu t'eja a we
Ile aiye to'wa a gbe
Lai f'ara gb'ara, f'ara kan'ra
You are your own competition
You are a light
Shine your light
Fan your flame
Up your game
Ditch the shame
Live up to yourself
Isé loògùn ìsé
Isé loògùn ìsé
Isé loògùn ìsé
Sisé
Isé loògùn ìsé
Isé loògùn ìsé
Isé loògùn ìsé
Sisé
Isé loògùn ìsé
Isé loògùn ìsé
Isé loògùn ìsé
Sisé
Isé loògùn ìsé
Isé loògùn ìsé
Isé loògùn ìsé
Sisé
Oh oh oh oh
Sisé Sisé Sisé Sisé (Work, Work)
Eni l'eti kogbo (He that has ears should listen)
Eni l'okan ko gba o (He that has heart should understand)
Work hard
Yes sir eh eh
Sisé