![Moni Jesu Loluwa](https://source.boomplaymusic.com/group10/M00/10/10/fcd3840ca5ac4a86aff5b6c367f4470aH3000W3000_464_464.jpg)
Moni Jesu Loluwa Lyrics
- Genre:Gospel
- Year of Release:2022
Lyrics
Moni Jesu L'oluwa o moti ni
Moni Jesu L'oluwa o mo lohùn
Gbogbo
Moní Jesu L'oluwa o moti ni
Moní Jesu L'oluwa o mo lohùn
Gbogbo
Nígbà mo mọ nire wa mi ri
Nigba mo mọ nire wọlé mi
Lọjọ mo mọ lẹ kun ni Dayo Jesu
Moni Jesu L'oluwa o moti ni
Moni Jesu L'oluwa o mo lohùn
Gbogbo
Boba ni Jesu Laye rẹ o wa
L'ohun gbogbo oo
Bo bá ní Jésù laye rẹ iya iya rẹ
A dopin
Bo bá ní Jésù laye rẹ wa l'ohun gbogbo óò
Bó bá ní Jésù laye rẹ iya rẹ a dopin
Biwọ bá le gbagbọ wa da'segun
Biwọ bá le gbagbọ wa ni'ye
Ayérayé
Bó bá ní Jésù laye rẹ o wa
L'ohun gbogbo oo
Bó bá ní Jésù láyé re
Iya rẹ a dopin
Moni Jesu L'oluwa o moti ni
Moni Jesu L'oluwa o mo lohùn
Gbogbo
Moní Jesu L'oluwa o moti ni
Moni Jesu L'oluwa o mo lohùn
Gbogbo
Igba mo mọ nire wa mi ri
Igba mo mọ nire wọlé mi
Lọjọ mo mọ lẹ kun mi Dayo Jesu
Moni Jesu L'oluwa o moti ni
Moni Jesu L'oluwa o mo lohùn
Gbogbo
Akirisore ni Jésù yíò Akirisore
Gbogbo bi to ba ti dé loti n sore
Akirisore ni Jésù yíò Akirisore
Gbogbo'bi to ba ti dé o loti n sore
Ni kenani o so'mi doti, Ṣe ohun
Lo laju afọju to'jioku Lasaru
Dìde ko'to wa f'ẹmi rẹ lelẹ fun'ẹṣẹ wa
Akirisore ni Jésù yíò Akirisore
Gbogbo'bi to bati de o loti n sore
Jesu o
Jesu lọna Jesu lọna Òtítọ àti iye
Too daju
Kristi lọnà kristi lọnà otito ati Iye toodaja
Akirisore asorekiri, Igba mo ti mọ laye mi ti dara Akirisore
Ìgbà moti mọ na rẹ l'ayé mi ti Leto asorekiri
Akirisore asorekiri, Igba mo ti mọ laye mi ti dara Akirisore
Ìgbà moti mọ na rẹ l'ayé mi ti Leto asorekiri
Oya e wa gbaa o
Olugbala
Jésù Ọmọ Ọlọrun
Olugbala
To wa sile ayé
Olugbala
A gun lọkọ legbe nitori emi tire
Won fun loti kikan mu nítorí
emi'tirẹ
A fun loti kikan mu ni
Olugbala
Ọrẹ ẹlẹsẹ
Olugbala
Nitori awa ẹlẹsẹ, agun lọkọ lẹgbẹ
Olugbala
Kawa ma bà segbé ka bàa lè yẹ
Olugbala
Yé wa gbaa o, Jesu nikan ni ona
Olugbala
Soti se tan lá ti gba
Olugbala
Oti ṣetan lati gba o