Alaanu Mi Lyrics
- Genre:Gospel
- Year of Release:2022
Lyrics
Kosohun to n jẹ ju ọpẹ lọ
Kosohun to jẹ ju ọpẹ lọ
Ọpẹ lounjẹ rẹ ìyìn l'ohunje rẹ
Kosohun to njẹ jo'pẹ lọ
Mo ronú jinlẹ̀ titi pe bi mo ba file pọti ti mọ fona ro'ka kín se
Oúnjẹ rẹ ni Ọlọrun mi
Oó gb'owo lọwọ mi fún èémí ti Mo n mi
Bẹẹ o gbeje lowo mi fún àbò rẹ
Lori mi lori ẹbi nigba gbogbo
Ni Mósè wipe o ṣe
Baaba Alaanu mi
Tal'a ba fio we ninu aye
Awọn alagbara pọ jan tirẹrẹ ṣugbọn iru rẹ ni o sí ọlọrun mi
Sebi iwọ lo dana sori papa
Papa njo ṣugbọn igbẹ o run
Aditu Nla ma sa lorọ rẹ
Apoti to seku Usa lo tun sọ
Obedi-edomu dọlọla,
Káábíèsí o ma si o Ọba Téní Kan o le bawi jọ ooo
Iwọ lororun aiku
Iwọ lororun aiṣa
Iwọ lororun aiti
Iwọ lororun airi
Akikitan, ayinyintan apeepetan Atabatubu
Oba teni kan o ridi rẹ
Oogo rẹ ti mọlẹ to, ogo rẹ ti Mọlẹ to o
Olutanju mi Alaanu Oluranlowo mi iwọ l'ọpẹ yẹ fún
Olutanju Alaanu mi Oluranlowo mi iwọ l'ọpẹ tosi o
Bẹ'da bamonu ro yíò ma fimoore ọlọrun
Mosún laṣalẹ o Jimi saye l'owurọ yi, agbara mi
Kọ aanu ni mo rigba awoni
Magbeje o ṣe olutanju ayé mi
Ose o
Olutanju mi Alaanu mi Oluranlowo mi iwo l'ope yefun O olutanju mi alaanu mi Oluranlowo Iwọ l'ọpẹ tosí o
Èmi o san tọrọ kọbọ fún èmí rè Ti mi mo n mi ọpọ lo n be Lọwọ ti nwọn sanwó èémí wọn
Ọlọrun bẹ Aye wo, Baba bami Muwon larada ki won o le yin Ọ Ki won o le se bi moti ṣe
Olutanju mi Alaanu mi Oluranlowo mi iwo l'ope ye Fún O olutanju mi Alaanu mi Oluranlowo mi iwọ l'ope tosí o
Lori ile mi lori ebi ni gbogbo Ana mi óo jen loju ẹkun ọlọrun
MiO lereke Ose, ogun ìdílé Dide lati dènà ogo rẹ l'ayé mi
Iwọ lo gbe mi leke o gbe mi Bori awọn ọta mi
Olutanju mi Alaanu mi Oluranlowo mi iwọ l'ọpẹ yẹ Fún o Olutanju mi Alaanu mi Oluranlowo mi iwọ l'ọpẹ yẹ Fún olutanju mi Alaanu mi Oluranlowo mi iwọ l'ọpẹ tọ si o
Modupe ore re lori Aye mi Alaanu mi mo m'ope wa
Modupe ore re lori Aye mi Alaanu mi o mo gbe ọ ga
Modupe ore re lori Aye mi Alaanu mi mo m'ope wa
Modupe ore re lori Aye mi Alaanu mi o mo gbe ọ ga
Ibiti o durosi fúnmi Tobi Oluwa boba jẹniyen won a ti Ma siregun
Apata igbala mi oseun o Alaanu Mi mo gbe o ga ga ga o
Modupe ore re lori Aye mi Alaanu mi mo m'ope wa
Modupe ore re lori Aye mi Alaanu mi o mo gbe ọ ga
Inu mi dun oluwa, inu dùn Ọlọrun
Inu mi dun oluwa,inu mi dun Ọlọrun mi
Akaika niye o l'ore to se funmi T'inu mi fi dun oluwa
Inu mi dun oluwa, inu dùn Ọlọrun mi
Inu mi dun oluwa,inu mi dun Ọlọrun mi
Akaika niye o l'ore to se funmi T'inu mi fi dun oluwa
Se ore jijẹ o laa fẹ sọ ni tabi ore Mimu oluwa oseun, iṣẹ rẹ toobi O lori Aye mi, ko ma lafiwe o Se Bàbá Mo n gun Moto Lojojumo B'ẹni mo ngun okada Kaa kiri, ẹ pade Nile'wosan óò Jẹ ko jẹ t'emi, e padi ni motuary Ko jẹ ko jẹ tiwa ati beebeelo, L'ore tio
Sefun mi, t'inu mi fi n dun
Olúwa
Inu mi dun oluwa, inu dùn Ọlọrun
Inu mi dun oluwa,inu mi dun Ọlọrun mi
Akaika niye o l'ore to se funmi T'inu mi fi dun oluwa
Ọlọrun ona ọpẹ mi pọ
Olorun ọna ọpẹ mi pọ
Ọnà ọpẹ mi pọ lọdọ rẹ baba Agba
Olorun ọna ọpẹ mi pọ
Ọlọrun ona ọpẹ mi pọ
Olorun ọna ọpẹ mi pọ
Ọnà ọpẹ mi pọ lọdọ rẹ kolounka
Olorun ọna ọpẹ mi pọ
Ọlọrun ona ọpẹ mi pọ
Olorun ọna ọpẹ mi pọ
Ọnà ọpẹ mi pọ lọdọ rẹ kolounka
Olorun ọna ọpẹ mi pọ
Gbope mi Jesu
Gbope gbope gbope gbope
Gbope mi o Baba
Agbanilagbatan
Gbope mio Baba Gbope mio
Baba
Atobajaye
Gbope o Baba
Ọlọrun Beulah
Ọlọrun Bàbá agba
Gbope mi o baba