Gbogbo Ogo Gbedu Lyrics
- Genre:Gospel
- Year of Release:2022
Lyrics
Gbogbo Ogo Gbedu - Bisimanuel
...
Igba ti a ro, ise iyanu re laye wa
A ripe Oga, a ripe oga
A ripe oo oga baba o
Igba ti a ro, ise iyanu re lori omo olojo ibi oo
A ripe Oga, a ripe oga
A ri pe e ga pupo ooo
Igba ti a ro, ise anu re laye wa
A ripe o ga lori Olarewaju
A ripe o ga ooo baba oooo yhe
Ni gba ti a ro ise Iyanu re laye wa
A ripe o ga (x2)
A ripe e gaa pupo