![Anu](https://source.boomplaymusic.com/group10/M00/05/30/64ab228c8983499cb6f710b88eae165e_464_464.webp)
Anu Lyrics
- Genre:World Music/Folklore
- Year of Release:2020
Lyrics
Anu - Bisimanuel
...
O God!Bisimanuel ti de oo ee eeiya O god/3x Ki ma ma ise tori mo dara abi tori mo mo adura aaaa gba oo aanu/3x ni morigba aa oo ki ma ma ise ti'le ti mo wa abi tori gbogbo iwe ti mo kaa oo aanu/3x ni morigba aa oo le le le le le le le oo kirakita ko do la oo ka sise bi eru oo ko da nkan if God no ku build a house alagbase se lasan_an ni oo eh eh as i dey waka you dey cover me oo omode mi o mo ile olodi o 'ki eni to ba pamo lo ku yo ninu ewu oo mo wa yan-an fa n da kiri oo eh Anu ni morigba,O lord na your mercy ****************************** ki ma ma ise tori mo dara abi tori mo mo adura aaaa gba oo aanu/3x ni morigba aa oo ki ma ma ise ti'le ti mo wa oo abi gbogbo iwe ti mo kaa oo aanu 3/x ni morigba aa oo Bi mo se n jade ni le aanu Bi mo se n ko le mo le oo aanu Bi mo se n bimo le'mo oo aanu bi mo se no sorire sere oo aanu/3x ni morigba aa oo Bisimanuel ti de oo