Igbala De Lyrics
- Genre:Gospel
- Year of Release:2022
Lyrics
Jesu Loni kemabo ewa gba'yo
Kristi Loni kemabo ore wa o
O nke tantan nigboro felese tose tan
Igbala de Igbala de o
Jesu Loni kemabo ewa gba'yo
Kristi Loni kemabo ore wa ooo
O nke tantan nigboro felese tose tan [2ce]
Igbala de o loni o ejekayo sese
Kristi was lati wagba awa elese la
Ona Miran ko ma si af'odo re
Jesu nikan lona iye ti gbogbo aiye nwa o [2ce]
Jesu Loni kemabo ewa gba'yo
Kristi Loni kemabo ore wa ooo
O nke tantan nigboro felese tose tan [2ce]
Odo Omi iye koti bikan San
Eyin t'ongbe ngbe ewa sibi Omi iye Yi
Kristi loni kema bo ajara tooto ni
Odo Omi iye koti bikan San mo
Eyin t'ongbe ngbe emabo sibi Omi iye
Odo Omi iye mare o fun gbogbo okan t'on p'ongbe
Jesu Loni kemabo ewa gba'yo
Kristi Loni kemabo ore wa ooo
O nke tantan nigboro felese tose tan [2ce]
Wa Omo Igbala wa
Asako Yara Pada wale
Jesu nfe o Jesu nfe o wa
Tete Yara mabo o nke tantan
Jesu Loni kemabo ewa gba'yo
Kristi Loni kemabo ore wa ooo
O nke tantan nigboro felese tosetan [4ce]