![Makanju](https://source.boomplaymusic.com/group10/M00/07/23/93ebbc85de29419bbba440e2d6269aa7_464_464.jpg)
Makanju Lyrics
- Genre:Gospel
- Year of Release:2022
Lyrics
Owe Oro re Ologbon a jo omoran amodi e
Aiya Ologbon mbe ni owo otun Olodumare Oba
Aiya asiwere mbe Lowo osi dragoni oba aye yi
Mo sebi owo otun Oluwa lagbega osi nsagbara sibe si
Eyin onisuru Lolorun ngbe Ibe lowa
Asan ni fe'niyan lati fo'kan fun isura aye yi
Ti tiiiiiiii yio fo lo ooo
Ounje fun inu, inu fo'unje adopin bodojo ojo kan laa pin
Ere kini fe'niyan to jere gbogbo aiye Yi ooo
towa-towa-towa-towa padanu ijoba orun
Ee mase kanju Owo
Ee mase kanju Ola
Ee mase kanju Ipo
Ee mase kanju Oro /3ce
Bojumo tinmo tolojo nkajo eda Jan o mo si
B'ola yio tiri eda kan o le so
Lala toroke sebi ile lon mbo oo
Owo Toni tiko le mu o de ijoba orun
Ile to ko to nipin ni ijoba orun
Ola Toni ipo towa Omo Taya re
Asan ninu asan ofutufete asan ni
Mole dogun mole diru aye lo mo
Mole dogun mole digba Asan laiye
Ee mase kanju Owo
Ee mase kanju Ola
Ee mase kanju Ipo
Ee mase kanju Oro /3ce
Lomumi ranti Okunrin olowo olola a'toloro o
Toloun fe ra agbara ebun emi mimo
Won ni kosegbe pelu ohun gbogbo to faiye yi kojo
Eniti o bani tan koto tan
Toba tan koni pe tan
Emase to isura jo fun ara yin laye yi o
Etete lepa ijoba Olorun na
Ohun Toba ku la o fi kun
Emase kanju Owo
Emase kanju Ola
Emase kanju Ipo
Emase kanju Oro /3ce