Jah Loruko Re ft. Harjovy Lyrics
- Genre:Gospel
- Year of Release:2022
Lyrics
Jah Loruko Re ft. Harjovy - Nuel
...
JIHMORHTA
( INSTRUMENTS PLAYING)
Gbangban igi ti alara idan
Oruko meta ti koyafaja
Edidi agbara ti o pamo sinu agbara
Akabi ka ola orun to San Ara
Omo nto lese ooh,
fun eni to se eke oooh
Amalarekereke oluwa lekelekere
Oba gbeni Leke lowo pelu ekun daye ooo
Omo alagbara ti osi je eni ite mole
Mohun lo lano sinu igbo Didi
kosi ona sibe ao pe lore aini
Oun toma jewariri egbe osuba fun
Pelu opo tiko mora jiji ekpe olu orun
Imole to tan si ona kpala kpala
kpala kpala
Afore Jani ninu woran horan
woran horan
Ajagun segun layi fitimose
Olori ogun wosi gbatemise
Ode aladewura oooo
Jah loruko re
okun ri osa, jordani pada seyin
Jah loruko re
sariwo oke ni waju zerubabeli
Jah loruko re
Awo oke nla nfo bi awo
jah loruko re
Adimula Adimuse
oruko re ile esho agbara
Olulana olugbala
oruko re Pelu igbagbo yio ja ide
(2X)
Glory and honour to the one who is to come
At the mention of your name every knee must bow to you(2X)
Ogbe ogo carry ogo
Alade ogo ma wole
ogbe ogo carry ogo ooo
Ataleka ajagurakabi(2X)
Ode obami de ooo
Ogbenu owode asola oooo
Ogbenu adelebo se ogo
ogbenu ketekete Pala ounfohun ni o ye eniyan
Okun ri osa jordani pada si enyin
oke nla nfo bi agbo orun nke Jah jah jah
Jah kira ilija oba olusegun de o
Jah loruko re
Iku Oro re da
Isa oku isegun re da oooo eh
Jah loruko re
Ajaloroni da Ara de ooo Akabikaola
Jah loruko re
Elimi jihmbhua lomi oluwa mi de ooo
Jah loruko re
Rabbi ooooo
Adimula Adimuse
oruko re ile isho agbara
Olulana olugbala
Oruko re Pelu igbagbo yio ja ide
Adimula Asemuise
oruko re ile isho agbara
Olulana olugbala
oruko re Pelu igbagbo yio ja ide