
Iro Ayo ft. Omotola Jayeola (Mr. Gbera) Lyrics
- Genre:Gospel
- Year of Release:2022
Lyrics
Iro Ayo ft. Omotola Jayeola (Mr. Gbera) - Mike Abdul
...
eh oh eh oh
ah oh oh
eh oh eh oh
ah oh oh
iro ayo la o ma gbo nile wa
sekere ilole ekun
igbagbo lo so wa da segun
let them know pa'loluwa
awa oni l'oju ekun [laye]
awa oni lereke ose
ore ofe oluwa towa
let them know pa'loluwa
see enu ope wa o'gbolude [o'gbolude]
òrun si ayo de o [saye]
ayo olorun sa l'agbara wa
wan ti mo pa'loluwa
iro ayo eh eh eh eh
iro ayo eh
iro ayo lawa nfe o
iro ayo eh
iro ayo ninu le wa
iro ayo nirin ajo wa
aro ayo lori ise wa
iro ayo eh
iro ayo ninu le mi
iro ayo nirin ajo mi
iro ayo lori ise mi
iro ayo eh
once has he spoken
twice have I heard
all power belongs to God
sing his praise with a shout of joy
mimo l'oluwa [mimo]
gbogbo aye kun ogo re [mimo]
awon orun wan wa riri [mimo]
almighty l'olorun wa
ayobami ayomide
ayomipo ayomikun
gbogbo ayo ni mo kojo sir
igbala ayo ti wole de
iro ayo eh eh eh eh
iro ayo eh
iro ayo lawa nfe o
iro ayo eh
iro ayo ninu le wa
iro ayo nirin ajo wa
iro ayo lori ise wa
iro ayo eh
iro ayo ninu le mi
iro ayo nirin ajo mi
iro ayo lori ise mi
iro ayo eh
ayo ayo ni mo gbede
eni ba ri mi e gb'ayo
eni ba gbo mi e gb'ayo
oun mbase ayo
ayo ni mo gbede
gbogbo oun mo dawo mi le
lo yori s're
kiise mimose
ore ofe s'a
ore ofe s'a o
eh eh eh eh
ayo ayo ni'se
ayo ni'se