
Jesu Mi Da Lyrics
- Genre:Afrobeats
- Year of Release:2020
Lyrics
Jesu Mi Daaaa - Mike Abdul
...
Intro:
Ọmọ ṣọọṣi wa
Oya ka Bible
Ma p’ojo t’orọ l’ana ṣe oun lo gbe Bible
(lo gbe Bible) (oya read it)
Ọmọ ṣọọṣi wa (Ọmọ ṣọọṣi wa)
Oya ka Bible (Oya ka Bible)
Ma p’ojo t’orọ l’ana ṣe oun lo gbe Bible
(lo gbe Bible)
The Bible says
O d’oju t’oṣo, (t’oṣo)
O d’oju t’ajẹ (O d’oju t’ajẹ)
Ẹni ti o n'iṣẹ, o fun n'iṣẹ
O s’agan d’ọlọmọ (O s’agan d’ọlọmọ)
Ohun l’o tun ori mi ṣe
Talki-na-do, a t'ori ṣe (a t'ori ṣe)
Ohun l’o gba mi la, Olugbala ti n’gb'ọmọ la (n’gb'ọmọ la)
Ṣ’o mọ ẹni t'o jẹ ko sun, (t'o jẹ ko sun)
T'o tun jẹ ko ji l'ayọ, (T'o tun jẹ ko ji l'ayọ)
Ṣ’o mọ bi t’o ti wa,
Ṣ’o mọ bi t’o ngbe (t'o ngbe)
Jesu mi da, Jesu mi re
Jesu mi da, Jesu mi re
O d’oju t’oṣo, (O d’oju t’oṣo)
O d’oju t’ajẹ (O d’oju t’ajẹ)
Alert ti wọle, (Alert ti wọle)
Jesu korede (Jesu korede)
Jesu mi da, Jesu mi re
Jesu mi da, Jesu mi re
Ma lọ wa o,
Ẹ sọ fun eṣu ko ma lọ wà. (ko ma lọ wa)
Ibi t’o de ’ṣẹ yẹn si, awa ọmọ Jesu a ti ja
Gbogbo ide ti ja,
Orúkọ Jesu la fi ja
Adura o ki pọ ju, ko sọ̀rọ̀ pe iyọ ti ja
Ninu ṣọọṣi ka ’wọ s'oke ko k’a Halleluyah,
Ninu ijọ wa, ṣ’adura nṣ'amin, ko s'ija n'ibẹ
Ọmọ ṣọọṣi wa (Ọmọ ṣọọṣi wa)
Oya ka Bible (Oya ka Bible)
Ma p’ojo t’orọ l’ana ṣe oun lo gbe Bible
(kúrò mbẹ)
Jesu mi da, Jesu mi re
Jesu mi da, Jesu mi re
O d’oju t’oṣo, (O d’oju t’oṣo)
O d’oju t’ajẹ (O d’oju t’ajẹ)
Alert ti wọle, (Alert ti wọle)
Jesu korede (Jesu korede)
Jesu mi da, Jesu mi re
Jesu mi da, Jesu mi re
Jesu, Jesu, Jesu – Jesu
O wa, O wa O wa – O wa
Favour yẹn pọ o pọ – O pọ
Alerti l'ẹsẹkẹsẹ – Aah
E concern you say ‘Yes Sir’ – Yes Sir
Ẹhn-ẹhn you are doing well – Yes Sir
Your miracle is on the way – Yes Sir
Gbas Gbos, I receive - Yes Sir
T’o ba n gbọ gbe gbe gbe (gbe gbe gbe)
Oluwa lo le gbe, (Oluwa lo le gbe)
Bukata aye rẹ, (gbe gbe gbe)
Oluwa lo le gbe (Oluwa lo le gbe)
Mummy ẹ gbe bọdi, (ẹ gbe bọdi)
Daddy ẹ gbẹ’sẹ now (ẹ gbẹ’sẹ now)
Ko ṣe duro wo, (Ko ṣe duro wo)
Ko ṣe duro wo (Ko ṣe duro wo)
Jesu mi da, Jesu mi re
Jesu mi da, Jesu mi re
O d’oju t’oṣo, (O d’oju t’oṣo)
O d’oju t’ajẹ (O d’oju t’ajẹ)
Alert ti wọle, (Alert ti wọle)
Jesu korede (Jesu korede)
Jesu mi da, Jesu mi re
Jesu mi da, Jesu mi re
Ṣ’o mọ ẹni t'o jẹ ko sun, (t'o jẹ ko sun)
T'o tun jẹ ko ji l'ayọ, (T'o tun jẹ ko ji l'ayọ)
Ṣ’o mọ bi t’o ti wa,
Ṣ’o mọ bi t’o ngbe (t'o ngbe)
Ṣ’o mọ ẹni t'o jẹ ko sun, (t'o jẹ ko sun)
T'o tun jẹ ko ji l'ayọ, (T'o tun jẹ ko ji l'ayọ)
Ṣ’o mọ bi t’o ti wa,
Ṣ’o mọ bi t’o ngbe (t'o ngbe)
Jesu mi da,
Jesu mi re
O d’oju t’oṣo
O d’oju t’ajẹ
Alert ti wọle,
Jesu korede
Jesu mi ree
Jesu mi ree....
End