Jeki Orun Si Lyrics
- Genre:Gospel
- Year of Release:2021
Lyrics
Jeki Orun Si - Emmanuel Babalola
...
Jeki orun si
Baba mi o
Jeki orun si
K’aye mi dara
Ki iji da’wo duro
K’ori mi so’re
Ki gbogbo aye
K’ole bami yin O l’ogo
Omo alaso ni mi, ki lo se ti mo ń wo akisa
Omo eleran ni mi, ki lo se ti mo ń je egungun
Omo elesin ni mi, ki lo se tí mo n run ni’le