![Jeki Orun Si](https://source.boomplaymusic.com/group10/M00/12/13/6a2d804795994aebaf715fc9c7ce1ec1_464_464.jpg)
Jeki Orun Si Lyrics
- Genre:Gospel
- Year of Release:2022
Lyrics
Jeki orun si
Baba mi o
Jeki orun si
Kori mi dara
Ki iji dawo duro
Korimi sore
Ki gbogbo aiye
Kan le bami yin o logo
Omo alaso ni mi
Kilose ti mo nwa kisa
Omo eleran ni mi
Kilose ti mo nje gungun
Omo alesin nimi
Kilose ti mo nrin nile
Jeki orun si oo
Kori mi sore