![Titilai (Forever)](https://source.boomplaymusic.com/group10/M00/02/06/60025a9f6d9b4edab96c4d7c7f2f19fcH3000W3000_464_464.jpg)
Titilai (Forever) Lyrics
- Genre:Gospel
- Year of Release:2017
Lyrics
Titilai Titilai Oluwa
Eyin ni awa yio ma yin o
Titilai Titilai Oluwa
Eyin ni awa yio ma yin o
Ayeraye eyin la o ma yin o
Ayeraye eyin la o ma gbega
Leyin re k'oma s'elomiran
Ife re k'oma laf'iwe
Ayeraye eyin la o ma yin o
Ayeraye eyin la o ma gbega
Leyin re k'oma s'elomiran
Ife re k'oma laf'iwe
Titilai Titilai Oluwa
Eyin ni awa yio ma yin o
Titilai Titilai Oluwa
Eyin ni awa yio ma yin o
Titilai Titilai Oluwa
Eyin ni awa yio ma yin o
For your faithfulness we really don't deserve
For the air we breath and the gift of life
For the peace you give our money can not pay for
Eyin ni awa yio ma yin o
Leyin re o, k'oma s'elomiran fun wa
Ife re k'oma laf'iwe
Titilai Titilai Oluwa
Eyin ni awa yio ma yin o
Titilai Titilai Oluwa
Eyin ni awa yio ma yin o
Titilai la o ma gbe o ga
Titilai o la o ma yin o logo
T'ori kos'elomiran Leyin re o fun wa
Eyin ni awa yio ma yin o
Titilai Titilai Oluwa
Eyin ni awa yio ma yin o
Titilai Titilai Oluwa
Eyin ni awa yio ma yin o
Ooh ooh ooh ooh
Eyin ni awa yio ma yin
Ooh ooh ooh ooh