![Waka Gospel Medley](https://source.boomplaymusic.com/group10/M00/02/06/47ede8efd8d04352846e7cb885dc62ffH3000W3000_464_464.jpg)
Waka Gospel Medley Lyrics
- Genre:Others
- Year of Release:2020
Lyrics
Hallelujah sa lorin wa t'aba de Paradise o
Hallelu hallelujah sa lorin wa o
Ta'ba de Paradise
Ta'ba dele
Ewa bawa gbe baba ga eyin ti e fe Jesu o
Ewa ba ewa bawa gbe baba ga o
Eyin ti e fe Jesu
Moni Hallelujah la o ma ko
Ta'ba de Paradise
Hallelu hallelujah sa lorin wa o
Ta'ba de Paradise
Ta'ba dele
Ewa bawa gbe baba ga eyin ti e F'Oluwa
Ewa ba ewa bawa gbe baba ga o
Eyin ti e fe Jesu e sun mo bi
Hallelujah oh oh, hallelujah
Hallelujah oh oh, hallelujah
Maa k'alleluya si baba mimo
Hallelujah
Maa k'alleluya si baba mimo
Hallelujah
Eh eh eh eh
Hallelujah oh oh, hallelujah
Hallelujah oh oh, hallelujah
Maa k'alleluya si baba mimo
Hallelujah
Maa k'alleluya si baba mimo
Hallelujah
Oya e je k'ayin Jesu, ka fiyin fun Oluwa
Ohun l'oba to rawa pada
Jesu o ma ku ise, ese o
Jesu o ma ku ise e o
Jesu o ma ku ise
Oya e je k'ayin Jesu, ka fiyin fun Oluwa
Ohun l'oba to gba wa la o
Jesu o ma ku ise, ese o
Jesu o ma ku ise e o
Jesu o ma ku ise
N'go fijo mi yin baba pelu atewo
N'go fijo mi yin baba pelu atewo
N'go fijo mi yin baba
Ma fo soke dupe o
N'go fijo mi yin baba pelu atewo
Oya eje ka jumo yin baba
Eje ka jumo yin baba
Ore t'ose laye wa o po
Jesu Kristi o ma ku ise
N'go fijo miyin baba pelu atewo
N'go fijo mi yin baba pelu atewo
N'go fijo miyin baba pelu atewo
N'go fijo mi yin baba
Ma ra baba San die
N'go fijo mi yin baba pelu atewo
Oya eje ka jumo yin baba
Eje ka jumo yin baba o
Ore t'ose laye wa o po
Jesu Kristi e ma ku ise
N'go fijo miyin baba pelu atewo
Ko mama ni baje o
Ile aye wa ko mama ni baje o
Lola Oluwa ko mama ni baje o
Ko mama ni baje o
Ile aye wa ko mama ni baje o
Lola Oluwa ko mama ni baje o
Ko mama ni baje o
Ile aye wa ko mama ni baje o o o
Lola Oluwa ko mama ni baje o
Ko mama ni baje o
Ile aye wa ko mama ni baje o
Lola Oluwa ko mama ni baje o
Jesu o Oruko to n gbani ni
Jesu o Oruko to n gbani ni
Kepe e o ohun lole gba o
Jesu o Oruko to n gbani ni
Kepe e o ohun lole gba o tan
Jesu o Oruko to n gbani ni
Jesu o Oruko to n gbani ni
Jesu o Oruko to n gbani ni
Ani ko kepe e o,ohun lole gba o
Jesu o Oruko to n gbani ni
Yi o see se adura lo maa gba
Yi o see se adura lo maa gba
Yi o see se adura lo maa gba o daju
Yi o see se adura lo maa gba
Toripe Aseti o si, fo'luwa
Aseti o si f'eni to ba n gbadura
Yi o see se adura lo maa gba
Aseti o si f'Oluwa
Aseti o si f'eni to ba n gbadura
Yi o see se adura lo maa gba
Solution ni mo n fe
Solution ni mo n fe o
Baba wa so
Baba wa solution soro mi
Solution ni mo n fe
Solution ni mo n fe
Solution ni mo n fe o
Baba wa so
Baba wa solution soro mi
Solution ni mo n fe
Jesu Kristi leni t'olorun ran
Alaanu fun gbogbo agbaye
Gbogbo igba toju n mo oba ti n mo
A o ma yin o ni Messiah
Jesu Kristi leni t'olorun ran
Alaanu fun gbogbo agbaye
Gbogbo igba toju n mo oba ti n mo
A o ma yin o ni Messiah
Jesu lore to'le gbani
Ore aye le koba o
Jesu yi lole mu o dele
Wa'gba Jesu k'ole layo
Esin lasan k'ole gbani
Ninu Jesu ni igbala wa
O n pe o wa mase duro pe
To'rola le peju fun o
Jesu Kristi leni t'olorun ran
Alaanu fun gbogbo agbaye
Gbogbo igba toju n mo oba ti n mo
A o ma yin o ni Messiah
Oya e gbe Jesu yi ga o
E gbe Jesu yi ga
E gbe Jesu yi ga se
E gbe Jesu yi ga
Oba nla to ra wa pada o
E gbe Jesu yi ga
Olorun nla to Wo wa San o
E gbe Jesu yi ga
Ohun lo da wa si doni o e
E gbe Jesu yi ga
Oya e gbe Jesu yi ga
E gbe Jesu yi ga
O gba kokoro lowo iku
E gbe Jesu yi ga
O tun gba ti isa oku araye e gbo o
E gbe Jesu yi ga