Hymn 176 Baba Palase Lyrics
- Genre:Gospel
- Year of Release:2017
Lyrics
Hymn 176 Baba Palase - Bukiemma
...
Baba palase latorun wa
ki gbogb' aye si wariri
Fun'jo mimo latorun wa
Ijoyi ni yio we aye mo
Aje, oso yio wariri
Labe agbara mimo yi
Awon Angel si kun fayo
Iyanu f'oko ikeyin
Halelluyah fun ise O-lu-wa.
Igba ikeyin na tide
Kristi Jesu yio pada wa
Lati wase'dajo aye
Iku Re Lori agbelebu
Eje ati oni to nsan
Kuro ninu iha mimo Re
Kogbodolo sori asan
Gbogbo oju yio si tun ri
Pelu awon Angeli mimo Re.
Kelese ronu piwada
f'ojo iwariri nla na
Awon Angel yio fun ipe
Ao ko ile at'orun
Okun yio do hun airi mo
Awon oku yio ji dide
Imiran pelu ayo nla
Imiran pelu ijiya
Elese yio wariri lojo na.
Awon t'oku f'oro Kristi
Awon toru Agbelebu Re
Won yio ji pelu ogo nla
Aowo won laso ogo
Ao dewon lade wura
Mariwo ope lowo won
Won yio fo pade Kristi won
Aare ki yio si fun won mo
Halelluyah li ohun Orin won.
Written by TRINITY
CCC hymn 176.