CCC Hymn 580 Nigbati ft. Sarah Diamond Lyrics
- Genre:Gospel
- Year of Release:2023
Lyrics
Nigbati fere Oluwa yio dun
Ti ise ki o si mo
A o pe ohun alaye igun merin wa
Lati fi ise won han
Niwaju Olugbala wa
Nigbati fere yio dun, emi o wa nibe
Nigbati, fere yio dun lohun
Nigbati, fere yio dun lohun
Nigbati, fere yio dun lohun
Nigbati, fere yio dun
Emi o wa nibe
Awa olurapada yio fo
T'are ki yio mu wa
Lati pade Olugbala Jesu Kristi
Awa yio wa ni abe iye Olorun titi aiye
Halleluya ni orin wa yio ma je
Nigbati, fere yio dun lohun
Nigbati, fere yio dun lohun
Nigbati, fere yio dun lohun
Nigbati, fere yio dun
Emi o wa nibe
Awa yio ma korin
Lat'owuro titi dale
Awa yio ma f'Ogo fun Olorun
Olugbala yio ma pe
Gbogbo wa ni omo rere
Nigbati fere yio dun, emi o wa nibe
Nigbati, fere yio dun lohun
Nigbati, fere yio dun lohun
Nigbati, fere yio dun lohun
Nigbati, fere yio dun
Emi o wa nibe
Nigbati, fere yio dun lohun
Nigbati, fere yio dun lohun
Nigbati, fere yio dun lohun
Nigbati, fere yio dun
Emi o wa nibe
Nigbati, fere yio dun
Emi o wa nibe
Nigbati, fere yio dun
Emi o wa nibe
Nigbati, fere yio dun
Emi o wa nibe