![Hallelujah](https://source.boomplaymusic.com/group10/M00/07/25/88b5abb7d8464366a9cdfd2bfa1eb46d_464_464.jpg)
Hallelujah Lyrics
- Genre:Gospel
- Year of Release:2020
Lyrics
Halleluyah, halleluyah
Halleluyah, baba o se
Halleluyah, mo dupe o
Halleluyah, jesu d'aiye o
Halleluyah, igbala ti d'aiye wa o
Ire, ire; ire o, ire, ire
Halleluyahhhhhhhhhhhhhhhh
Halleluyah, mo dupe o
Halleluyah, jesu d'aiye o
Halleluyah, igbala ti d'aiye wa o
Ire, ire
N'ilu jerusalem,
Ire, ire
L'egbe judea,
Ire, ire
N'ibuje eran o,
Ire, ire
E ho, l'abi jesu si o,
Ire, re
Ore, l'abi jesu si o,
Ire, ire
Everybody tele mi k'alo
Halleluyah, mo dupe o
Halleluyah, jesu d'aiye o
Halleluyah, igbala ti d'aiye wa o
Ire, ire
Omo maria, ire, ire
Aya josefu,
Ire, ire
Josefu, to n se carpenter, ire, ire
Hmmm, n'ilu jerusalem, ire, ire
Aaaa, l'egbe judea, ire, ire
Aaaa, aaaa, n'ibuje eran o,
Ire, ire
Aaaa, aaaa, l'abi jesu si o, ire, ire
Ehoo, l'abi Jesu si o eeeba,
Ire, ire
E korin, everybody tele mi k'alo
Halleluyah, mo dupe o
Halleluyah, jesu d'aiye o
Halleluyah, igbala ti d'aiye wa o
Ire, ire
Halleluyah, mo dupe o
Halleluyah, jesu d'aiye o
Halleluyah, igbala ti d'aiye wa o
Ire, ire
Halleluyah, mo dupe o
Halleluyah, jesu d'aiye o
Halleluyah, igbala ti d'aiye wa o
Ire, Ire
Omo maria, ire, ire
Aya josefu,
Ire, ire
Josefu, to nse carpenter ire, ire
Hmmm, n'ilu jerusalem, ire, ire
Aaaa, l'egbe judea, ire, ire
Aaaa, aaaa, n'ibuje eran o, ire, ire
Aaaa, Aaaa, l'abi jesu si o, ire, ire
Ehoo, l'abi jesu si o, eeeba ire, ire
E korin, everybody tele mi k'alo
Halleluyah, mo dupe o
Halleluyah, jesu d'aiye o
Halleluyah, igbala ti d'aiye wa o
Ire, Ire
Halleluyah, mo dupe o
Halleluyah, jesu d'aiye o
Halleluyah, igbala ti d'aiye wa o
Ire, Ire
Halleluyah, mo upe o
Halleluyah, jesu d'aiye o
Halleluyah, igbala ti d'aiye wa o
Ire, ire