Eyin Ni Imole Lyrics
- Genre:Gospel
- Year of Release:2020
Lyrics
Eyin n'imole aiye
Jesu ti so fun yin
Ilu t'ako s'ori oke
Ko le fara sin
Eyin n'imole aiye
Eyin n'imole aiye
Jesu ti so fun yin
Ilu t'ako s'ori oke
Ko le fara sin
Eyin n'imole aiye
A ki tan fitila
Ka gbe s'abe osuwon o
E je ka je imole
Ninu okunkun biri aiye yi
Alaigbagbo nwo yin
Oju oluwa nwo yin o
Jesu n'imole wa
Awa si n'imole aiye, nitoripe
Eyin n'imole aiye
Jesu ti so fun yin
Ilu t'ako s'ori oke
Ko Le Fara Sin
Eyin n'imole aiye
T'iwo ba gbe ounje
F'eniti ebi npa
To te Alaini l'orun
To fi rere san buburu o
Iwo n'imole aiye
Ti jesu so fun wa
Ilu t'ako s'ori oke
Ko le fara sin
Iwo n'imole aiye, nitoripe
Eyin n'imole aiye
Jesu ti so fun yin
Ilu t'ako s'ori oke
Ko le fara sin
Eyin n'imole aiye
Ki n'ibasepo re
Pelu alaigbagbo
Je k'imole re tan
K'iwo si yin baba l'ogo
Kede jesu kakiri
Royin ise igbala to se
P'alaigbagbo wa s'agbo
K'ale jo de ade ogo, n'ikehin
Eyin n'imole aiye
Jesu ti so fun yin
Ilu t'ako s'ori oke
Ko le fara sin
Eyin n'imole aiye
B'aiye nbi yin lere, ewi
Bi won nbi yin lere, e so
Wipe jesu to gba yin la lo je
Ki eyin je imole aiye
E je k'oro ise yin tan ka
Pe'mole aiye leyin je o, nitoripe
Eyin n'imole aiye
Jesu ti so fun yin
Ilu t'ako s'ori oke
Ko le fara sin
Eyin n'imole aiye
B'aiye nbi yin lere se ewi
Bi won nbi yin lere, e so
Wipe jesu to gba yin la lo je
Ki eyin je imole aiye
E je ki oro ise yin tan ka
Pe'mole aiye leyin je o, nitoripe
Eyin n'imole aiye
Jesu ti so fun yin
Ilu T'ako S'Ori Oke
Ko Le Fara Sin
Eyin n'imole aiye, nitoripe
Eyin n'imole aiye
Jesu ti so fun yin
Ilu t'ako s'ori ke
Ko le fara sin
Eyin n'imole aiye