Igba Iponju La Nmo Ore Lyrics
- Genre:Fuji
- Year of Release:2012
Lyrics
Igba Iponju La Nmo Ore - King Dr. Saheed Osupa
...
Chorus : Eni shoro ba koni mo ri
Ire koni po a o ko
Igbaponju la n mo ore o
Kajo fokele run be, ka tun jo fororo jesu.
All : Eni shoro ba koni mo ri
Ire koni po a o ko
Igbaponju la n mo ore o
Kajo fokele run be, ka tun jo fororo jesu.
Seri ore meji ko ngbakan, wodijo wa won n peja
Ikan ma lowo e n de, ikeji owo e ode
Sewa reyi towo e n de iyen ma lon n Peja
To n fun ikeji je.
Bo ti e jasin lo n pa nigbaya, sibesibe won n pin je,
Chorus : Eni shoro ba koni mo ri
Ire koni po a o ko
Igbaponju la n mo ore o
Kajo fokele run be, ka tun jo fororo jesu.
All : Eni shoro ba koni mo ri
Ire koni po a o ko
Igbaponju la n mo ore o
Kajo fokele run be, ka tun jo fororo jesu.
Shoda be lowo n de, ntemi lowo e o de,
Ntemi towo e o de, kerekere owo n de,
Oti wa fe di igberaga,
Aaa Sewa oniwa sa la n hu o,bowo o i dowo Eni.
Chorus : Eni shoro ba koni mo ri
Ire koni po a o ko
Igbaponju la n mo ore o
Kajo fokele run be, ka tun jo fororo jesu.
All : Eni shoro ba koni mo ri
Ire koni po a o ko
Igbaponju la n mo ore o
Kajo fokele run be, ka tun jo fororo jesu.
....... Asiere tiwa gbagbe Ana awon ti o ri nigba yen,
Lowa n pe ko wa jeja, tan ba de tiwa jeja
Won a ma yo ore e yen,
Amo gbogbo won ti wa gbagbe, pe ba ala o le la leni
Ni base o se ni ana.
Chorus : Eni shoro ba koni mo ri
Ire koni po a o ko
Igbaponju la n mo ore o
Kajo fokele run be, ka tun jo fororo jesu.
All :Eni shoro ba koni mo ri
Ire koni po a o ko
Igbaponju la n mo ore o
Kajo fokele run be, ka tun jo for oro jesu.
Kadupe lowo oba to laye to fi nini gba aini lowo wa,
Ero Ota gan Lori wa bi ka teba ko lobe,
Ka gbabo obe wa sile won.
Chorus : Eni shoro ba koni mo ri
Ire koni po a o ko
Igbaponju la n mo ore o
Kajo fokele run be, ka tun jo fororo jesu.
All : Eni shoro ba koni mo ri
Ire koni po a o ko
Igbaponju la n mo ore o
Kajo fokele run be, ka tun jo fororo jesu.
Kadupe lowo oba to laye to fi gbeda o Lara wa,
Won ti fe fenu pa na ola,
Bose n fena ma lo n ke, tori olorun ma lo n kan po si,
Chorus : Eni shoro ba koni mo ri
Ire koni po a o ko
Igbaponju la n mo ore o
Kajo fokele run be, ka tun jo fororo jesu.
All : Eni shoro ba koni mo ri
Ire koni po a o ko
Igbaponju la n mo ore o
Kajo fokele run be, ka tun jo fororo jesu.
Few : Kajo fokele run be o,
All : Katun fororo je su,
Few : Kajo fororo je su, x3
All : katun jo fororo je su, x3
Few : Kajo fokele run be o,
All : katun jo fororo je su.