Kokoro Alate I Lyrics
- Genre:Fuji
- Year of Release:2015
Lyrics
Asese beere oo ani ki le ti ri oo
Asese berre kile ti ri
Ashi ma goke si tori ibi giga laye temi
O sure ju pe ti alakantu ba ku
Lati bi de du oma tun taku lo da do
Wa do awaye atun ma tawe o
Tori moti so ni gba kan
Moti ni feyi soyi kan ko ni tan
Pe ko ni tan ni ile alatanku lai lai
O sure ju pe ti alakantu ba ku
Lati bi de du oma tun taku lo da do
Wa do awaye atun ma tawe o
Tori tipe tipe niyen
Lati ko falisko 1, ta ko fuji blues
Tako demonstrations, tako master, ta tun ko trebul solo
Ki lo tun wa wu wo ton tu le ju orin wa
Jojumo jojumo sha lopon tawa sun
Ko se duro wo bo se’n lo lo ba tele
Tori moti so nigba kan
Moti ni gba saheed don pe sa ye nobody knows tomorrow
Ola de tun le pe ju
Shey bi ola na loti yi pada to di eni
Ko ti wa di pe eni gan ma di ola
Ko se duro wo bo si lo ma tele
Tori ati bi lo no n ani
Lati bi lo titi de ilu London
To fi de America gbogbo aiye ma ti mo
Pe osupa saheedi oba loju to pa wo
Oju to pa wo ko ma yi wo poster ni
Won w ani noka ko to ma fawa won wo
To’supa bay o gbogbo aiye ti mope mode oo
Bi yo kele kuro ni mushin ati tan de oyigbo
Bi pe tu la’merica lati London won a wole
Bo je London lati Germany won a ya de
Oju to pa wo ko ma yi wo poster ni
Won w ani na ka ko to ma fawa y obo
To sup aba yo gbogbo aye to mo pe mode
Oya kokoro alate toun ta te ni
Owu alate toun tate ni
Tete popo abohun de lorun sha laye oni ka lu ku
Loti ni ti ti e lara
Kokoro alate toun ta te ni
Owu alate toun tate ni
Tete popo abohun de lorun sha laye oni ka lu ku
Loti ni ti ti e lara
Kokoro alate toun ta te ni
Owu alate toun tate ni
Tete popo abohun de lorun sha laye oni ka lu ku
Loti ni ti ti e lara
Kokoro alate toun ta te ni
Owu alate toun tate ni
Tete popo abohun de lorun sha laye oni ka lu ku
Loti ni ti ti e lara
Sheri lojo eni baba suliya
Awon theatre practitioners yi lan korin fun
Ki tie se awon, awa theatre practitioners ni
To’n fi ere ita je ko everybody logbon
S’he wa ri lojo oni o
Ati okurin pelu obirin, to’n be nibi
Mofe ko ri nkan mud ani lo le
Lo je kin ko orin ti mo’n ko saheed osupa
Ti mo ni
Kokoro alate toun ta te ni
Owu alate toun tate ni
Tete popo abohun de lorun sha laye oni ka lu ku
Loti ni ti ti e lara
Kokoro alate toun ta te ni
Owu alate toun tate ni
Tete popo abohun de lorun sha laye oni ka lu ku
Loti ni ti ti e lara
Kokoro alate toun ta te ni
Owu alate toun tate ni
Tete popo abohun de lorun sha laye oni ka lu ku
Loti ni ti ti e lara
E gbo na talo mo’n na
Talo mo’n a ta lo mon a oo
Ta lo mo na ki lo’birin fe
Obirin fe telorun, okurin ole fun
Ati wa jo gbe po bawo le se mo la le se?
Ke se ma ni fun obirin pelu okurin
E tu gbo na talo mo’na
E gbo Na talo mo’na
Ki lo’kunrin o fe
Okurin o fe a fo ju di
Iwa obirin de ni yen
Ati wa jo gbe po