
Jesu Olubaso Okan Mi/ Eyin Egbe Serafu Lyrics
- Genre:Gospel
- Year of Release:2020
Lyrics
Jesu Olubaso Okan Mi/ Eyin Egbe Serafu - Emmanuel Somuyiwa
...
jesu lolubaso okan mi
ore tiko le komi sile
oba tin so ekundayo
olutunu okan mi
Jehova nisi Oluwa
opagun mi modupe
fun dasile ijo mimo
tosoju emimi
larin ota larin idamu
oko fimi fun iji aye
ah Oluwa mi
modupe modupe
Jehova nisi oluwa
opagun mi modupe
fun dasile ijo mimo
tosoju emimi