Aidibaje Lyrics
- Genre:Gospel
- Year of Release:2025
Lyrics
Aidibaje - Adeyinka Alaseyori
...
Toluwa nile ati ekun re
Aye ati Oun gbogbo to redo sinu re
Iyin ogo fo’ruko re
Toluwa nile ati ekun re
O gbe’le aye kale sori omi
Iba,
Eni to ti wa shaju awon oke
Ibugbe wa lati Iran di’ran
Gbogbo ogo fo’ruko re
Aidibaje, Olorun ti ibaje o le kan
Aidibaje o, aditu ni o
O ti n be ki aye o ti wa waa si maa be nigba ti aye o ni si
Aidibaje Olorun agbalagba iba o
Interlude
Ninu re lati da Oun gbogbo
Eyi a foju ri ta o foju ri
Ite, Agbara, Ijoba
Gbogbo re la da ninu re
Nipase re lati ba Oun gbogbo laja
Eje agbelebu lo fi pari ija
Akobi lati’nu ogun wa
Eni ti n se itan shan ogo re
Ati aworan Oun tikara re o
Ola nla lo wo ni aso
Aidibaje, Olorun ti ibaje o le kan
Aidibaje o, aditu ni o
O ti n be ki aye o ti wa waa si Maa be nigba ti aye o ni si
Aidibaje Olorun agbalagba iba o
Aidibaje, Olorun ti ibaje o le kan
Aidibaje o, aditu ni o
O ti n be ki aye o ti wa waa si Maa be nigba ti aye o ni si
Aidibaje Olorun agbalagba iba o
Orun mbe ninu orun
Aye mbe ninu aye
Eyan tun wa ninu eniyan
Olorun ni Ko baje ri o
Majemu ti o le pin ninu ara re lo wa o
Oni majemu ayo
Oba to n kiri sore
To n sore kiri
Moti re ni gboju le
Mo ti reni feyinti
Feyinti feyin feyinti
Orun mbe ninu orun
Aye mbe ninu aye
Eyan tun wa ninu eniyan
Olorun ni Ko baje ri o
Majemu ti o le pin ninu ara re lo wa o
Aidibaje, Olorun ti ibaje o le kan
Aidibaje o, aditu ni o
O ti n be ki aye o ti wa waa si Maa be nigba ti aye o ni si mo
Aidibaje Olorun agbalagba iba o
Aidibaje, Olorun ti ibaje o le kan
Aidibaje o, aditu ni o
O ti n be ki aye o ti wa waa si Maa be nigba ti aye o ni si mo
Aidibaje Olorun agbalagba iba o
Aidibaje, Olorun ti ibaje o le kan
Aidibaje o, aditu ni o
O ti n be ki aye o ti wa waa si Maa be nigba ti aye o ni si mo
Aidibaje Olorun agbalagba iba o