![Aboogun Ni](https://source.boomplaymusic.com/group10/M00/07/08/e27846d6f32b4433a7d4b116d69922cc_464_464.jpg)
Aboogun Ni Lyrics
- Genre:Gospel
- Year of Release:2023
Lyrics
Aboogun Ni - Adeyinka Alaseyori
...
alleluyah
eeeeeeeeh
o n ni,o n ko
oro mi da ri'yan ji'jan
igba wo lo bere
to fi wa do'go agbaye,
oun atiraka se,anu se f'emi ni irorun,
aye pe e lo'gun,kabiesi ni yinka mojo'gun lo.
o n ni,o n ko
oro te'mi da ri'yan ji'yan,
aye n pariwo,igba wo lo o o bere o,
t
o ti wa do'go agbaye,
alleluyah
oun atiraka se,anu se fun ni'rorun,
aye pe e lo'gun,kabiesi ni mojo'gun lo.
o n ni,o n ko
o ni ni,o n ko
oro mi da ri'yan ji'yan
igba wo lo bere
to ti wa do'go agbaye,
oun atiraka se,anu se fun ni'rorun,
aye pe lo'gun,kabiesi ni ojo'gun lo.(2×).
abogun ni
oun la'raye ke
won o mo pe iwo lasiri mi o,
o n ni,o n ni eeeh
o n ni,o n ko
oro mi da ri'yan ji'yan
igba wo lo bere
to ti wa do'go agbaye,
oun atiraka se,anu se fun ni'rorun,
the man at the beautiful gate
he was at the beautiful gate,but his life was not beautiful,
but when he met with Peter and John,
when he were going to the temple
they looked at him,and he looked at them,
silver and gold i have none,
but in the name of Jesus,
arise and walk,
everyone in the church,they were looking at him,
and they were asking,
is he the one,is he not the one,
eeeeeeh
nigbati won ba bere,si n ri omo ninu re,
ti inu re ga lojiji,iwo ti won ni o le bi mo,
o koja,first trimester
o koja,second trimester,
o koja,third trimester,
won wa ni o n ni,o n ko
oro re da ri'yan ji'yan,
awon to ti sare koja re lo tele tele,
to ba did ninu ere,ti adaniwaye gbe o lejika,
ti o je ko lakaka,to wa mu o rinrin ajo ninu ogo
awon to ti saaju re lo,to wa n ba won,to koja won,
David wipe,Oluwa se kii le won,Olorun le won,
o ni se mo ma ba'won,Olorun ni o ma bawon,
o ni se mo ma koja won,Olorun ni o ma koja won.
eeeeeh
but should recover and overtake,
ni bibeli so fun David,
igba wo lo bere
to ti wa do'go agbaye,
oun aye tiraka se,anu se fun ni'rorun
aye pe lo'gun,kabiesi ni ojo'gun lo.
abogun ni
oun la'raye ke,won o mo pe iwo lasiri mi o,
Olorun iwo ni.