![Ijebu (Juju Yoruba)](https://source.boomplaymusic.com/group1/M00/0B/9D/rBEeMVhRRrmAVOYNAADfm4SJD_A015.jpg)
Ijebu (Juju Yoruba) Lyrics
- Genre:Juju
- Year of Release:1969
Lyrics
Otawa oniroju o
Erege iroju atokunbo emora
Otawa oniroju o
Erege iroju atokunbo emora
Iro lerego npa
Erege iroju atokunbo emora
Eko lerego se o
Erege iroju atokunbo emora
Gbogbo omo ondo onipofo
Erege iroju atokunbo emora
Ebami ki mokun o
Erege iroju atokunbo emora
Moju moju ko ma moju
Erege iroju atokunbo emora
Kokoro lo jewon loju
Erege iroju atokunbo emora
Yinmu yinmu koma yinmu
Erege iroju atokunbo emora
Kokoro lo jewon loju
Erege iroju atokunbo emora
Oun to basowo kon rere oja je
Erege iroju atokunbo emora
Ebami ki mokun oh eh
Ondo ondo eko ni bokun oh eh
Juli ose omo oloye eh ondo o ondo edi bokun o e
Onile gogoro onile gogoro
Onile gogoro juliana tiwa
Onile gogoro onile gogoro
Onile gogoro juliana dada
Ewe bami bami la o ibafo 2x
Juliana mi o bami la o ibafo
Eki bokun o bami la o ibafo
Ogbo mo seje jeka debe o 2x
Eyan lo logbomosho
Ilu ogbomosho ko ni baje
Eyan lo logbomosho
Ilu ogbomosho ko ni baje
Ayinde o ayinde o ayinde oto
Ori mi mama je fayinde ere gun
Eda mi mama je fayinde sere o eh
Ogbomoso o oyakalo2x
Kajo fewure diyan
Nile oya moni nile aije o
Akanmu ji
Talosope a oni baba o
Wa gbamileti koto mope moni baba o
Ayinde o se opo ibugi
Oba gbamileti pere koto mope moni baba o