Aimasiko Lo N Damu Eda Lyrics
- Genre:Juju
- Year of Release:1987
Lyrics
Instrumentals
Aimo asiko lo n’damu eda o
Oro mi l’owo oluwa lowa
Aimo asiko lo n’damu eda o
Oro mi l’owo oluwa lowa
Aimo asiko lo n’damu eda o
Oro mi l’owo oluwa lowa
Aimo asiko lo n’damu eda o
Oro mi l’owo oluwa lowa
Instrumentals
Ale ale ko le ale momi rara
Moti l’ala feyinti mo r’oluwa
Oro mi l’owo oluwa lowa
Aimo asiko lo n’damu eda o
Oro mi l’owo oluwa lowa
Ale ale ko le ale momi rara
Moti l’ala feyinti mo r’oluwa
Oro mi l’owo oluwa lowa
Aimo asiko lo n’damu eda o
Oro mi l’owo oluwa lowa
Kini geduge fe f’igi ogede gbe
Kil’ategun fe figi gedu se
Oro mi l’owo oluwa lowa
Aimo asiko lo n’damu eda o
Oro mi l’owo oluwa lowa
Kini geduge fe f’igi ogede gbe
Kil’ategun fe figi gedu se
Oro mi l’owo oluwa lowa
Aimo asiko lo n’damu eda o
Oro mi l’owo oluwa lowa
Eni rowo e loju
Ala to ronu
Eni ko tepa mose e
Ni tori ebi
Oro mi l’owo oluwa lowa
Aimo asiko lo n’damu eda o
Oro mi l’owo oluwa lowa
Eni rowo e loju
Ala to ronu
Eni ko tepa mose e
Ni tori ebi
Oro gbogbo l’owo oluwa lowa
Aimo asiko lo n’damu eda o
Oro mi l’owo oluwa lowa
Ire temi ko ma ni koja mi
Ire temi ko ma ni koja mi
Wa ba mi se baba
Ko ma koja mi
Wa ba mi se baba
Ko ma koja mi o laye
Aimo asiko lo n’damu eda o
Oro mi l’owo oluwa lowa
Ire ti e ko ma ni koja e
Ire ti e ko ma ni koja e
To ba ti fe kori
So f’eledumare
Ile lofe ko
So f’eledumare
Ogbon lofe ni
So f’eledumare
Aya lofe ni so f’eledumare
Owo lofe ni
So f’eledumare
Baba ese o
Baba ese o
A yan ju e
Asese o laye
Aimo asiko lo n’damu eda o
Oro mi l’owo oluwa lowa
Oro akoba
Oba ma je ka ri
Oro adaba
Oba ma je ka ri
Oro gidi ni
Es’ ami adura
Oro gidi ni
Es’ ami adura
Won ni kob’sami
Lojo si ose fari
Won ni kob’sami
Lojo si ose fari
Osu dulo
Osu opo
Osu dulo
Otun solomi sororo
Aimo asiko lo n’damu eda o
Oro mi l’owo oluwa lowa
Oro gidi ni
Es’ ami adura
Oro gidi ni
Es’ ami adura
Oro akoba
Oba ma je ka ri
Oro adaba
Oba ma je ka ri
Won ni kob’sami
Lojo si ose fari
Won ni kob’sami
Lojo si ose fari
Osu dulo
Osu opo
Osu dulo
Otun solomi sororo
Aimo asiko lo n’damu eda o
Oro mi l’owo oluwa lowa
Esami adura yi o
Karaiye ma koba wa
Esami adura yi o
Karaiye ma koba wa
Esami adura yi o
Karaiye ma koba wa
instrumentals
Chief brethren mi igbinedion
Osamwren igbinedion
Oko seri igbinedion
Esama mi igbinedion
Osawaru igbinedion 2x
Esama mi igbinedion
Esama igbinedion
Esama igbinedion (continuously with prestigious names)
Okada igbinedion 4x
***
Okada igbinedion
***
Okada igbinedion
***
Okada igbinedion