
Ajokodabi Ile (Juju/High-Life) Lyrics
- Genre:Juju
- Year of Release:1969
Lyrics
Gbogbo ileku kan tepa mose
Gbogbo ileku sa won lo lowo
Gbogbo ileku kan tepa mose
Gbogbo ileku sa won lo lowo
Ijebu omo alare won dara
Ijebu omo alare won seniyan
Ijebu omo alare won dara
Ijebu omo alare won seniyan
Kekere ijebu o owo ni owo ni
Agba ijebu o owo ni owo ni
Eweso o eweso o 2x
Ile mise logoje mi gojo sejo
Omo alare eweso o
Ema bolurawi kema ba jiya
Iwa nilayode amasigbodu
Olayode omosibodu
Awo oke omosibodu
Eweso o eweso o 2x
Ile mise logoje mi gojo sejo
Omo alare eweso o
Eweso o eweso o
Omo alare ewese o
***
Eweso o eweso o
Omo alare ewese o
***
Eweso o eweso o
Omo alare ewese o