
Egba (Juju Yoruba) Lyrics
- Genre:Juju
- Year of Release:1969
Lyrics
Awa lomo Abeokuta
Ilu rere ilu olola
Ibi gbogbo losan nilu wa
Egba omo ilu saki
Awa lomo Abeokuta
Ilu rere ilu olola
Ibi gbogbo losan nilu wa
Egba omo ilu saki
Te ba fe molumo
E lo seba folumo
Te ba fe molumo
E lo seba folumo
Teba ti de giga
E duro wapa otun e
Teba ti de giga
E duro wapa otun e
Ona wo le o gbe baje oni ke o 2x
Egba jaiye ofi tedo si
Kawon ni baba 2x
Fun awon toku lehin
Ema deno deba o
Igba eranko yi deno teko
Ekun baba eranko
Eba mi ki ore mi oko Elizabeth
Igba eranko yi deno teko
Ekun baba eranko
***
Igba eranko yi deno teko
Ekun baba eranko
***
Igba eshinshin ni deno teko
Lowo baba eshinshin
***
Igba eshinshin ni deno teko
Lowo baba eshinshin
***
Igba eranko yi deno teko
Ekun baba eranko
***
Igba eshinshin ni deno teko
Lowo baba eshinshin