- Genre:Juju
- Year of Release:1977
Lyrics
Olojo oni o iba
Ajuba kato sere
Olojo oni o iba
Ajuba kato sere
Agbagba ilu o iba
Ajuba kato sere
Agbagba ilu o iba
Ajuba kato sere
Omode ilu o iba
Ajuba kato sere
Omode ilu o iba
Ajuba kato sere
Bomode bati juba foluwa
Ona ala ire awole
Bomode bati juba foluwa
Ona ala ire awole
Balagba bati juba foluwa
Ona ala ire awole
Balagba bati juba foluwa
Ona ala ire awole
Boju majojuba kiba mise o
Mojuba o iba iba fomode ilu
Mojuba o iba iba fagbagba ilu
Mojuba o iba iba fomode ilu
Mojuba o iba iba fagbagba ilu
Mojuba o iba iba fomode ilu
Mojuba o iba iba fagbagba ilu
Mojuba o iba iba fomode ilu
Mojuba o iba iba fagbagba ilu
Mojuba o iba iba fomode ilu
Mojuba o iba iba fagbagba ilu
Mojuba o iba iba fomode ilu
Mojuba o iba iba fagbagba ilu
Bomode bati juba foluwa
Ona ala ire awole
Balagba bati juba foluwa
Ona ala ire awole
Bomode bati juba foluwa
Ona ala ire awole
Balagba bati juba foluwa
Ona ala ire awole
Boju majojuba kiba mise o
Mojuba o iba iba fomode ilu
Mojuba o iba iba fagbagba ilu
Mojuba o iba iba fomode ilu
Mojuba o iba iba fagbagba ilu
Mojuba o iba iba fomode ilu
Mojuba o iba iba fagbagba ilu
Mojuba o iba iba fomode ilu
Mojuba o iba iba fagbagba ilu
Mojuba o iba iba fomode ilu
Mojuba o iba iba fagbagba ilu
Mojuba o iba iba fomode ilu
Mojuba o iba iba fagbagba ilu
Iru eko tawa yi o
Igi lo dabe olumo
Okola alajimi sanusi
Iru eko tawa yi o
Igi lo dabe olumo
Okola alajimi sanusi
Teba fera irin
Tabi building materials
Labe olumo
Lori ile o
Tabi eko ile
Toba je reekado esara sasa
Doromo sanusi
Awon sani baba awon sani baba 2x
Ah leko leba oluyole o
Awon sani baba
Onitemi atata
Alaji mi o abdul atata olajide nko
Oko alhaja mi dakun
Suliatu mi arewo
Oko alhaja ose simbiatu mi
(name praises)
Awon sani baba awon sani baba 2x
Ah leko leba oluyole o
Awon sani baba
Alhaji mi sanusi
Eni peki wa ma logba gbajumo e
Egba ile egba ona agbe e dele won
Lori oke olumo o omo sanusi
Onitemi atata ransack mi olola
Lori oke olumo o omo sanusi
***
Lori oke olumo o omo sanusi
***
Lori oke olumo o omo sanusi
***
Lori oke olumo o omo sanusi
***
Lori oke olumo o omo sanusi
***
Lori oke olumo o omo sanusi
***
Lori oke olumo o omo sanusi
(praises)
Lori oke olumo o omo sanusi 2x
***
Lori oke olumo o omo sanusi
***
Lori oke olumo o omo sanusi
***
Lori oke olumo o omo sanusi