Baba Fana Han Wa Lyrics
- Genre:Juju
- Year of Release:1977
Lyrics
Baba wa eledumare
Baba fana han wa
Baba wa eledumare
Baba fana han wa
A foloke arin nile
Amage leshin lona baba
Baba wa eledumare
Baba fana han wa
A foloke arin nile
Amage leshin lona baba
Baba wa eledumare
Baba fana han wa
An wo moto
An foloke
Amage leshin lona baba
Baba wa eledumare
Baba fana han wa
Taba wa lofurufu
Abi tababe lori omi
Baba wa eledumare
Baba fana han wa
Kama fopatele
Fopatele nigujebo
Baba wa eledumare
Baba fana han wa
Ojo melo lo lo laiye
Bami wewu iri
Baba wa eledumare
Baba fana han wa
Ilu abete tawon elegan lo
Baba ni oje o dun
Bankole ilu abete tawon elegan lo
Baba ni oje o dun
Bankole ose ko baje ti
Ko baje iro ni won pa
Layiwola bose ko baje ni
Ko baje iro ni won pa
Layiwola bose ko baje ni
Ko baje iro ni won pa
Ah gbogbo lanla kokofefe won
Iro lo jasi
Gbogbo lanla kokofefe won iro lo jasi
Awon keni mama ni eniyan
Alajekenu bi ediye niyen
Gbogbo lanla kokofefe won iro lo jasi
Awon to binu layiwola mi bankole
Gbogbo lanla kokofefe won iro lo jasi
Awo alhaji mi o alhaji mi balis nko
Gbogbo lanla kokofefe won iro lo jasi
***
Gbogbo lanla kokofefe won iro lo jasi
***
Gbogbo lanla kokofefe won iro lo jasi
***
Gbogbo lanla kokofefe won iro lo jasi
***
Gbogbo lanla kokofefe won iro lo jasi
***
Gbogbo lanla kokofefe won iro lo jasi
***
Gbogbo lanla kokofefe won iro lo jasi
Layiwola alani omo bankle
Alase frates agencies
Toba fese larin bankole
Ofurufu ni abi dojuomi
Boloko ile ajibanisi onitemi e nimi o
Ah odogbo niyeye lo ija mi ni
Ah odogbo niyeye lo ija mi tan
Awon to binu alala mi o
Omo bankole
Odogbo niyeye lo ija mi tan
***
Odogbo niyeye lo ija mi tan
***
Odogbo niyeye lo ija mi tan
***
Odogbo niyeye lo ija mi tan
***
Odogbo niyeye lo ija mi tan
***
Odogbo niyeye lo ija mi tan
***
Odogbo niyeye lo ija mi tan
Saanu mi o olugbala saanu mi olugbala
Saanu mi olugbala ma je baiye lo
Saanu mi o olugbala saanu mi olugbala
Saanu mi olugbala ma je baiye lo
Eni to ba te laiye a baye lo 2x
Eni to ba te lesi a besi lo 2x
Saanu mi o olugbala saanu mi olugbala
Saanu mi olugbala ma je baiye lo
Eni lowo lo lara 3x
Ori mi ma gbagbe adehun wa
Eda mi ma gbagbe adehun wa
Eni lowo lo lara 3x
Ori mi ma gbagbe adehun wa
Eda mi ma gbagbe adehun wa
Eni lowo laiye mo
Oluwa fun mi ni temi
Ki ma sasiko waye o
Kimasako bata fegbe mi o
Eni lowo laiye mo
Edumare fun mi ni temi
Ki ma sasiko waye o
Kimasako bata fegbe mi o
Asako ferere
Nitori ko se mimo
Awobis mo ferere
Nitori ko se mimo
Eni lowo laiye mo
Edumare fun mi ni temi
Ki ma sasiko waye o
Kimasako bata fegbe mi o
Opo eniyan lofe toloro
Gbogbo eniyan lo fe doloro
Mofe lowo mofe kole
Mofe kole mofe ra moto
Mofe lowo mofe kole
Mofe kole mofe ra moto
Mofe lowo mofe kole
Mofe kole mofe ra moto
Eni lowo laiye mo
Edumare fun mi ni temi
Ki ma sasiko waye o
Kimasako bata fegbe mi o
Eni lowo laiye mo
Edumare fun mi ni temi
Ki ma sasiko waye o
Kimasako bata fegbe mi o
Ori lafin kole
Ori lafin meran lawo
Aseju osi feledumare
Ye maje mosi
Ye maje moya
Ori maje mosi
Eda mi maje moya
Ye maje mosi
Ye maje moya
Ori maje mosi
Eda mi maje moya
Ori mi maje mosi
Ori mi o
Eda mi o ori mi o
Ori mi ma je moya ori mi o
Ori mi ma gbagbe mi se ori mi o
Ori mi ma je mosi ori mi o
Ori mi magbagbe mi o ori mi o
Eda mi ma gbagbe mi o ori mi o
Ori mi maje moya ori mi o
Eda mi maje mosi ori mi o…
Alhaji danjuma lagege 2x
Danjuma cinema lagege
Alhaji danjuma lagege
Danjua supermarket lagege
Alhaji danjuma lagege
***
Alhaji danjuma lagege
***
Alhaji danjuma lagege
***
Alhaji danjuma lagege
***
Alhaji danjuma lagege
***
Alhaji danjuma lagege