
Iba O Messiah Oba Lyrics
- Genre:Juju
- Year of Release:1988
Lyrics
Iba O Messiah Oba - Chief Commander Ebenezer Obey
...
Iba o Messiah oba, Mo juba e
Laye mi, baba ko ranmi lowo kaye ye mi
Laye mi, baba ko ranmi lowo kinu mi dun, kin ma moshi baba,
Iba o Messiah oba, mo juba e
Mofi towotowo juba re o, Eleduwa oba
Oba tiipe koyeni
oyigiyigi, oba Edumare,
Mofi towotowo juba re o, Eleduwa oba
Iba o Messiah oba mojuba e
Ngo sunmo Olorun, ngo sunmo o
Botilese iponju lomumi wa o,
Sibesibe, ngo ma korin sunmo o sunmo
Olorun sunmo odo e
Iba o Messiah oba mojuba e
Awa fijo, awa f'ayo korin soba rere
Ayeraye Olorun oun logbe mi
leke'danwo gbogbo
Awa yo yo nnu ore re, awa yo si lagogo
Lagogo e hoo, lagogo eyoo
Bi a ba seni loore, ope laada o, o seun,
Iba o Messiah oba mojuba e
Awa fijo, awa f'ayo korin soba rere
Ayeraye Olorun oun logbe mi leke'danwo gbogbo
Awa yo yo nnu ore re, awa yo si lagogo
Lagogo e hoo, lagogo eyoo
Bi a ba seni loore, ope laada o, o seun,
Iba o Messiah oba mojuba e
Iba o Messiah oba mojuba e
Yeo ,Yeo ,Yeo, Ah !Jesu Kristi oba
olojo oni o, madoju tiwa o,
Ah Jesu Kristi oba
Yeo, Yeo, Yeo, Ah! Jesu Kristi oba
olojo oni o, madoju tiwa o,
Ah Jesu Kristi oba
Jesu ni darijiwon o Baba nitori won o mo ohun ti won n se
Sugbon ao rira, ao rira, ao tun rari lojo ajinde
Iba o Messiah oba mojuba e
Yungba,Yungba, yo yo yo
A dun joyin lo
Aye mi adun adun adun, a dun joyin lo
Emi n gbo gbare gbare gbare
Maritemi gba, Emi n gbo gbare gbare gbare
Ire owo, emi n gbo gbare gbare gbare
Ire omo, emi n gbo gbare gbare gbare
Ire alaafia, emi n gbo gbare gbare gbare Ayo atidunnu, emi n gbo gbare gbare gbare
Mari temi gba, emi n gbo gbare gbare gbare
Omo Olorun ko gbodo yodi,
Rara o, rara o, rara o, rara
oro ti o nilaari ore mi, mee lowo si
oro rohun rohun, rederede, jatijati, jagbajagba,
oro ti o ni laari ore mi, mee lowo si.
Toba n gbo gbare gbare
Emi n gbo gbare gbare gbare
Mari temi gba, emi n gbo gbare gbare gbare
Satan shame unto you ,all powers belong to Jesus,
Satan shame unto you o, all powers belong to Jesus ..............