Motun Gbe De Lyrics
- Genre:Juju
- Year of Release:1973
Lyrics
Mo tun gbe de
Ere oloyin momo
Number yin yato
Moma tun gbe de
Mo tun gbe de
Ere oloyin momo
Number yin yato
Moma tun gbe de
Instrumentals
Mo tun gbe de
Ere oloyin momo
Number yin yato
Moma tun gbe de
Mo tun gbe de
Ere oloyin momo
Number yin yato
Moma tun gbe de
Eniyan mi o
Mo wa fe sotan kan
Eteti egba mi gbo
Eniyan mi o
Mo wa fe sotan kan
Eteti egba mi gbo
Baba kan laiye ati jo
Ogbon loruko e
Oni iyawo meji
Kolowo kosi bimo
Osise sise
Odabi pe ko bosi
Orele adahun se
Odabi pe ko bosi
Orele onisegun odabi pe ko bosi
Toba teledumare lo
Instrumentals
Ogbon s’alaiye f’eledumare
Oni eledumare
Nijo toti dahun saiye
Ohun sise sise
Ohun rele adahunse
Ohun rele onisegun
Amo ko bosi
Ohun o lowo l’owo
Ohun osi bimo
Eledumare
Eleti gbaroye ni
Eledumare
Eleti gbaroye ni
Toba koun merin
Ko kofu baba yen
Ko gbodo mu jukan lo
Ose kisa
Ose kisa ni o
Baba wa orun se kisa
O fun wa ni jije
O fun wa ni mimu
Baba wa orun se kisa
O se kisa o se kisa o
Baba wa orun se kisa
Ose kisa
Eleduwa oba mimo
Baba wa orun se kisa
Eledumare
Eleti gbaroye ni
Eledumare
Eleti gbaroye ni
Toba koun merin
Ko kofu baba yen
Ko gbodo mu jukan lo
Ohun akoko
Iyen lowo
Eyi ekeji
Iyen omo
Ohun eketa suru baba iwa
Aiku lewe
Iyen lo sikerin
Ogbon pe yawo kekere
O ka laiye o se fun
Gbo ewo lo ye ka mu
Ninu owo pelu omo
Suru baba iwa
Aiku lewe
A o gbodo mu jukan lo
Were ni iyawo ti dahun
Owo lama mu
Were ni iyawo ti dahun
Owo lama mu
Ogbon ni tori kini
Iyawo ni taba mowo
Owo arowo rakuba
Awon akole
Aso asiko
Besi oloja
Iyen aje t’awon
Aiye awon ti dara
Ogbon dupe lowo iyawo kekere
Otun pe iyawo keji
Toba onyesefun
Ewo loyekamu
Ninu owo pelu omo
Suru baba iwa
Aiku lewe
A o gbodo mu ju kan lo
Iyawo keji
Oun ni iyale
Iyawo keji
Oun ni iyale
Oun ni ogbon oko mi
Omo lama mu
Omo ni Pataki
Omo lope aiye
Ijo tati fera
Oun o bimo
Omo lo se koko
Ogbon tun dupe lowo iyawo keji
Oba tu ke si ore e
Ok’aliye o se fun
Ngbon ohun loye ka mu
Ninu owo pelu omo
Suru baba iwa
Aiku lewe
A o gbodo mu ju kan lo
Ore e ba dalohun
Oni ogbon ore mi
Aiku lewe
Lo dara lati mu
Toba mu aiku lewe
Wa pelaiye
Wa dagbalagba
Wa tun darugbo
Ogbon tun dupe lowo ore e
O wa ke si awon obi e
Won tun salaiye fun wo
Ngbon ohun loye ko mu
Ninu owo pelu omo
Suru baba iwa
Aiku lewe
A o gbodo mu ju kan lo
Mama pelu baba e
Won ba fun lesi
Won ni suru
Lo dara lati mu
Mama pelu baba e
Won ba fun lesi
Won ni suru
Lo dara lati mu
Ogbon pa ti baba pelu mama e
O so f’eledumare
Oni suru lohun ma mu
Instrumentals
Iyawo keji akoko
Eyi to mo omo ku
Loba be mama pelu baba
Oni ofe korin
Owa tenu bo orin
Owipe
Omo o omo o omowunmi yeye
Omo laso
Omo o omo o omowunmi yeye
Omo laso
Oni olomo lo laiye
Ore mi o
Omo niyi o
Omo o omo o omowunmi yeye
Omo laso
Omo omo si
Omo la arowon ere
Omo o omo o omowunmi yeye
Omo laso
Omo omo si
Omo la fe aiye
Omo o omo o omowunmi yeye
Omo laso
Amo sibe sibe
Ogbon okunrin okun
Ogbon pa ti mama pelu baba e
Oso feledumare
Oni suru lohun mamu
Eledumare
O fun ni suru
Owa ko meta toku
Okojo sajule orun
Nigba to dijo kan
Owo k’eledumare
Oni oluwa
Oti mo daju wipe
Suru lore mi
Ibikibi toma lo
Mofe balo
Kajo magbe
Oluwa ki ohun gbaowo
Olo ba suru
Ogbon tun dolowo
Nigba to tun dijo kan
Omo pe eledumare
Oni oluwa
Oti mo daju wipe
Owo lore mi
Ibikibi to ba ma lo
Ajo nlo ni
Kajo ma gbe
Lodo eledumare
Oku aiku lewe ni kan
Otun salaie feledumare
Oni awon egbe hun
Ounfe lo bawon
Ohun ole danikan gbele
Eledumare tun yola aiku lewe
Wipe ko lobawon
Bi ere bi ere
Ogbon to oun ni suru
Ojogun owo
Ojogun omo
Pelu aiku lewe
Idi itan mi nipe
Gbogbo oun ti aba se
Kafi suru fun
Idi itan mi nipe
Gbogbo oun ti aba se
Kafi suru fun
Suru lo dara
Suru lo dara
Suru suru
Suru lo dara
Gbogbo oun ti aba se
Kafi suru fun
Suru suru
Suru lo dara
Eni toba ni suru
Oun gbogbo loni
Suru suru
Suru lo dara
Eni toba ti ni suru
Oun gbogbo loni
Suru suru
Suru lo dara
Suru suru o
Suru lo dara
Instrumentals
Kanju kanju
Ema se kanju mo
Esopele soun lo dara kanju kanju
Ema se kanju mo
Esopele soun lo dara
Eni to ba gun moto
Tabi eni to be lokukun
Iba je keke
Tabi eni ton fe serin
Ninu gbogbo oun ti a ba se
Tori oju kikon oun
Koba logbojo oru
Oju onikan osupa
Ko jade ni osan gan gan
Oju ki ko irawo
Ko jade si osan gan gan
Suru lo dara
Suru lo dara
Suru suru
Suru lo dara
Gbogbo oun ti aba se
Kafi suru fun
Suru suru
Suru lo dara
Suru suru
Suru lo dara (till fade)