
KÒTÍGHÀ Lyrics
- Genre:World Music/Folklore
- Year of Release:2024
Lyrics
Hmmm uh hmm
Hmmm uh hmm
Dande
Hmmm
Cento ain't normal
Yeah
Back in the street mọ ni kọtíghà
Mo wọlé ni ilàjẹ mọ ni kọtíghà
Ẹyin temi ni AB junction Mọ̀ ni Kọtíghà
Ẹyin tí ẹ̀ lìké mi nkò mọ̀ ní Kọtíghà
What kind of language I am speaking in my music these days
Fún àwọn DJ's tó gbé mi sọrí on a replay, ah
Mọ̀ mọ̀ pé orin yìí sí má jà wọ́ sà
Páwò páwò bí ọmọ Otedola mọ́ sí má páwò sà
Mọ́ kí arán temi nígbórọ́ ó ní ojá yìí
Àrán kan tí má mí but àrán kan fẹ́ ká salàyè
Màyé, bomb my màyé
Every night and day mi o kí salàyè
Fímílẹ̀ kí má lọ jọ̀r ma pòn kún sí mí ló rù
Wọn ní rap mi o dá but wọn gbọ torú torú
Da chain sọ̀rú èklípìsì ọ̀rùn
Everyday mo hun gbadura bá wo ni kò sẹ́ ni de ọrun
E rọra sẹ́, kè má lọ jálẹ
Ké má lọ pa yan, kẹ́ má ṣe òtẹ́ aráyín
Ọmọ Ilaje ayémáfúgẹ̀ ayé kan ló wà
Ọ wà kú lọ wọ orí
E rọra sẹ́ kè má lọ jálẹ
Ké má lọ pa yan, kẹ́ má ṣe òtẹ́ aráyín
Ọmọ Ilaje ayémáfúgẹ̀ ayé kan ló wà
Ọ wà kú lọ wọ orí rí wà
Kọ̀tígháà kọ̀tíghà kọ̀tíghà arán tẹmi rán kọ̀tíghà
(kọ̀tíghà)
Kọ̀tígháà kọ̀tíghà kọ̀tíghà abúró mi rán kọ̀tíghà
(kọ̀tíghà Okay)
Kọ̀tígháà kọ̀tíghà kọ̀tíghà hustlers rán yii kọ̀tíghà
(kọ̀tíghà)
Kọ̀tígháà kọ̀tíghà kọ̀tíghà omayemi rán kọ̀tíghà
(kọ̀tíghà)
Wọ ti jà kràkrà jù, dángbànà jù
Eyan Sodiq ni rẹ o, o ti fẹ lọ gbọn jù
Malo ma kàn jùjù, kò má lọ ṣẹ̀ àṣẹjù
Aye ó fẹ́ní fún ọ̀rọ̀ o, mo sẹ́ n ṣẹ́pa mo hustle
Ọmúrọ́ ti wọlé ni ránlórùn han sọ pé mo dé
Different patterns every year giddem like Sarkodie
Me I no come here come deh play
Omo tí ó gbón, kò má le ṣẹ́ o
E fi mílẹ̀ kí mà pa rọ̀ ló, máámì kò má sí holiday
E rọra sẹ́, kè má lọ jálẹ
Ké má lọ pa yan, kẹ́ má ṣe òtẹ́ aráyín
Ọmọ Ilaje ayémáfúgẹ̀ ayé kan ló wà
Ọ wà kú lọ wọ orí
E rọra sẹ́, kè má lọ jálẹ
Ké má lọ pa yan, kẹ́ má ṣe òtẹ́ aráyín
Ọmọ Ilaje ayémáfúgẹ̀ ayé kan ló wà
Ọ wà kú lọ wọ orí rí wà
Kọ̀tígháà kọ̀tíghà kọ̀tíghà arán tẹmi rán kọ̀tíghà
(kọ̀tíghà)
Kọ̀tígháà kọ̀tíghà kọ̀tíghà abúró mi rán kọ̀tíghà
(kọ̀tíghà)
Kọ̀tígháà kọ̀tíghà kọ̀tíghà hustlers rán yii kọ̀tíghà
(kọ̀tíghà)
Kọ̀tígháà kọ̀tíghà kọ̀tíghà omayemi rán kọ̀tíghà
(kọ̀tíghà)