Baby Jọ Lyrics
- Genre:Others
- Year of Release:2016
Lyrics
It's Keenah-Kay Chekwas
Mmmmmmm ahhhhhhhh
Ìwọ nikan ṣoṣo
Ìwọ nikan ṣoṣo
Tí mo fẹ
Baby, jọ̀ ó
Má fi mílẹ̀
Dúró tì mí
Jọ̀ má sálọ
Baby, jọ̀ ó
Dúró tì mí
Má fi mí sílẹ̀
Jọ̀ má sálọ
Baby, jọ̀ ó
Má fi mílẹ̀
Dúró tì mí
Jọ̀ má sálọ
Baby, jọ̀ ó
You are my world
You are my california baby (baby baby)
California
Baby, jọ̀ ó
Má fi mí ṣe gòbé
Má fi mí ṣe wàyò
Bí antenna (bí antenna)
You lie to me I let it slide
You hurt me I take it in stride
I put up with a lot of things
La la la la la la
And when it gets too much
I pack my things and say that
I am going, leaving, moving on
Then you run after me
And say that you are sorry
That baby, baby, baby
Baby, jọ̀ ó
Má fi mílẹ̀
Dúró tì mí
Jọ̀ má sálọ
Baby, jọ̀ ó
You are my world
You are my california baby (baby baby)
California
Baby, jọ̀ ó
Má fi mí ṣe gòbé
You are my eminado eminado eminado
I try to comprehend it all
The journey that we had so far
So fairytale and nightmare-like
Oh oh oh oh oh oh
My feelings when hurt were your muse
When I was down, you were happy, dancing
Glad at heart
Then you run after me
And say that you are sorry
That baby, baby, baby
Baby, jọ̀ ó
Má fi mílẹ̀
Dúró tì mí
Jọ̀ má sálọ
Baby, jọ̀ ó
You are my world
You are my california baby (baby baby)
California
Baby, jọ̀ ó
Má fi mí ṣe gòbé
You are my eminado eminado eminado
Then you say
Adunni t'emi (oh yeah)
Ifẹ́ t'emi (títí láíláí)
Olólùfẹ́ mi (ohhhhhhh)
Adunni t'emi (ohhhhhhh)
Adùnbi t'emi (ọ̀kan ṣoṣo)
Adùkẹ́ t'emi, (t'emi tirẹ)
Abèní baby (títí láíláí)
Ìwọ ẹmí, hmmm (títí láíláí)
You'll be begging me to stay
Keenah-Kay Chekwas
Are you feeling the gbedu
Are you feeling the gbedu
Are you feeling the gbedu