- Genre:Afrobeats
- Year of Release:2001
Lyrics
So Fun Mi - Dr. Victor Olaiya
...
Anti so fun mi (Bimbo)
Ki n le fe o o
Pinolu sun mo mi (ani se)
Ko ye lo ma rin kiri
Ani se fun mi
Obe to gbaladun
Pinolu mi, iwo ni nsa ma fe
Iyawo n'iya, s'ogba wipe mo mo
Wa mi wa fun'toju
Wa mi wa fun money
Bimbo, gb'ona to wu mi, ki n le wa e o
Wa mi wa fun'toju
Anise, wa mi wa fun money
Ani se fun mi, Pinolu
Obe to gbaladun
Bimbo mi, iwo ni nsa ma fe
Ani se fun mi, Bimbo
Obe to gbaladun
Dear mi, iwo ni nsa ma fe
So fun mi, Pinolu
Ki n le fe o o
Bimbo, sun mo mi (ani se)
Iwo ni nsa ma fe
Iyawo n'iya, s'ogba wipe mo mo
Wa mi wa fun'toju (Bimbo)
Wa mi wa fun money
Ani gb'ona to wu mi, ki n le wa e o
Wa mi wa fun'toju
Wa mi wa fun money
Anti, so fun mi (ani k'o tun se fun mi)
Obe to gbaladun
Dear mi (ani se) Iwo ni nsa ma fe