- Genre:Afrobeats
- Year of Release:2001
Lyrics
Ilu Le O - Dr. Victor Olaiya
...
(instrumental)
ilu le o, ko sowo lode
ilu le o, ko sowo lode
obinrin nkigbe okunrin nkigbe
kaluku lon kede owo
obinrin nkigbe okunrin nkigbe
kaluku lon kede owo
Bi sisi mura gege wa ka e mole
Bi sisi mura gege wa ka e mole
mo bere e titi won o jise fun e ni
iro lon pa o
owo lon wa yen
mo bere e titi won o jise fun e ni
iro lon pa o
naira lon wa yen
(instrumental)
ilu le o ko sowo lode
ilu le o ko sowo lode
obinrin nkigbe okunrin nkigbe
kaluku lon kede owo
obinrin nkigbe okunrin nkigbe
kalu ku lon kede owo
(instrumental)
bi sisi mura gege wa ka e mole
bi sisi mura gege wa ka e mole
mo bere e titi won o jise fun e ni
iro lon pa o
owo lon wa yen
mo bere e titi won jise fun e ni
iro lon pa o
naira lon wa yen
(instrumental)