
Omo Ekun Lyrics
- Genre:R&B
- Year of Release:2024
This song is not currently available in your region.
Lyrics
Omo Ekun - Hondread
...
Ifa mo pon leyin re
Ela mo pon leyin re
Gidi gidi gbam bi ose o
Gidi gidi gbam bi ose o
Ifa mo pon leyin re
Opele ko ni gbe ra re
Ko gbe ra re no le
Adifa fun orunmila
Baba nlo irin ajo ojo
Baba mu lenge omo awo re lowo oo
Iku laja orunmila lekun
Iku ko ni je mo le yin lekun pa je
Iku o le ri le yin lekun pa je
Iku ko ni je mo le yin lekun pa je
Iku o le ri le yin lekun pa je
Ifa mo pon leyin re
Ela mo pon leyin re
Gidi gidi gbam bi ose o
Gidi gidi gbam bi ose o
Ifa mo pon leyin re
Ifa mo pon leyin re
Hondread or nothing