
IBA Lyrics
- Genre:Others
- Year of Release:2023
Lyrics
Iba
Akoda aye
Iba
Aseda orun
Iba
Iba fun awon to laye
Iba
Iba awon irunmole
Iba
Mo ju ba Ori mi
Iba
Iba baba ati yeye
Iba
Eji ki iba mi se
Iba
Iba ni mo se
Iba ni mo se
Omode o le me ko je ko ma ra lowo
Iba ni mo se
Iba ni mo se
Oso ile aje ile
Iba esu odara
Onile orita
O be lokun sun kun
Ke 'ru o be lokun
Esu ma se mi omo elomi ni o se
Ogun lakaye osimole
Olomi ni le o fe je we
Ola 'so ni le fi mo kimo bora
Onile ko jun ko jun
Obatala obatarisa
Oba ta kun ta kun lode iranje
Baba arugbo
Iba
Akoda aye
Iba
Aseda orun
Iba
Iba fun awon to laye
Iba
Iba awon irunmole
Iba
Mo ju ba Ori mi
Iba
Iba baba ati yeye
Iba
Eji ki iba mi se
Iba
Sango o olukoso
Ayara e no
Oko Oya
E ba'n fun l'obi ooo
Be ba wo 'ya be ro 'ya mo
E wa lo si so obi
O n kere e nu
Be ba wo 'ya be ro 'ya mo
E wa lo si iso aro
O n re 'so re dudu
Awon iya mi oo
E ye ba ge ba ge
Olokiki oru o
E ma je n se yin o
Iba abeni ile afokoyeri
Alapo ire ton pe ni alapo ika
Yeeee yeeeee
Iba
Akoda aye
Iba
Aseda orun
Iba
Iba fun awon to laye
Iba
Iba awon irunmole
Iba
Mo ju ba Ori mi
Iba
Iba baba ati yeye
Iba
Eji ki iba mi se
Iba
Iba
Iba
Iba
Iba
Iba
Iba
Iba
Iba