OGO Lyrics
- Genre:Gospel
- Year of Release:2024
Lyrics
Ogo ni f'olorun loke orun
Ati alaafia si awon eniyan re
Lori ile aye
Ogo ni f'olorun loke orun
Ati alaafia si awon eniyan re
Lori ile aye
Ogo ni !!
Ogo ni !!
Ogo ni !!
Ogo ni !!
Oluwa ,olorun ,
Oba orun . Olodumare ati baba Asiyan
Adupe fun o , awayin yo o fun ogo re
Ogo Ni f'olorun like orun
Ati alaafia si awon eniyan re
Lori ile aye
Ogo Ni f'olorun like orun
Ati alaafia si awon eniyan re
Lori ile aye
Ogo ni !!
Ogo ni !!
Ogo ni !!
Ogo ni !!
Oluwa Jesu Kristi
Omo baba kansoso
Oluwa olorun ,odo agutan olorun
Iwo ni tonko ese aiye lo
Gba adura wa
Ogo Ni f'olorun like orun
Ati alaafia si awon eniyan re
Lori ile aye
Ogo Ni f'olorun like orun
Ati alaafia si awon eniyan re
Lori ile aye
Iwo joko lowo otun baba saanufunwa
Nitori Iwo nikan eni mimo
Iwo nikani oluwa . Iwo ni kansoso Ni oga ogo julo
Jesu Kristi pelu emi mimo,ninu ogo baba
Amin
Amin o
Amin o
Amin
Amin
Amin o
Amin o (eh!)
Amin o