![MA JE NWO BI ORUN](https://source.boomplaymusic.com/group10/M00/02/28/0534ebcd097d4a35bd605bdf8fbb08a1_464_464.jpg)
MA JE NWO BI ORUN Lyrics
- Genre:Gospel
- Year of Release:2024
Lyrics
BI MO TI N RAN BI ORUN OBA MA JE NWO BI ORUN OBA RERE BI MO TI NRAN BI ORUN OBA MA JE N WO BI ORUN OBA RERE SANU AYE MI K'AYE MA F'ENU BA 'RAWO MI JE SANU AYE MI O KI NMA P'ITAN OGO NINU OFO BI MO TI N RAN BI ORUN OBA MA JE NWO BI ORUN OBA RERE