![Oluwosan(Healer)](https://source.boomplaymusic.com/group10/M00/09/21/f9feff3e486b48129bfe96f98952fd99_464_464.jpg)
Oluwosan(Healer) Lyrics
- Genre:Gospel
- Year of Release:2022
Lyrics
ALAYANMO ORUN GBA MI MODE
BAMI T'AYANMO MI SE OO
KO TO S'IMI K'EMI O MO
ONIWOSAN
SIBE SIBE K'ARA MI MA MA DA
BAMI T'AYANMO MI SE OOO
AWON TI WON GAN ONI MI
JE K'OLA MI GBA 'DOBALE WON
OLORUN MOSE KAN LE DA O MO
P'ARA L'OKU O EMI O KU
SARIDU ALLAH NA SIDJARUKARAMIH
MOTEKU ALELEFALI JIRIBUBAWAH SIDAMOMIFALIRAH
OLUWOSAN ORUN GBA MI
MODE
KOTO SIMI KI N MO 'NIWOSAN O
KARA MI MA MA DA
KO TO SIMI O O O
KO TO SIMI OMO IYIN
OLORUN MOSE
ORIMOLADE YII O
DIDE TAGBARA TAGBARA
DIDE TOGO TOGO
OLURANLOWO AYANMO MI DA
EDIDE E E E
ERANMI LOWO
AWON TI WON GAN ONI MI
JE K'OLA MI GBA 'DOBALE WON
OLORUN MOSE KAN LE DA O MON
P'ARA LOKU OO
EMI O KU....
Angeli mi o ni sun