![Ju Wura (Album Version)](https://source.boomplaymusic.com/group10/M00/02/21/25e1c6438b214b0b855217e852022ce5_464_464.jpg)
Ju Wura (Album Version) Lyrics
- Genre:Gospel
- Year of Release:2024
Lyrics
Ohun ta ni O ju wura lo o
Ehn
Ogo ta ni o ju wura lo o
Ehn
Ohun ta ni O ju wura lo o
Ehn
Ogo ta ni o ju wura lo o
Ehn
A ti ra wa pada
A ti d'omo
Omo ileri
A ti jogun iye
Ainipekun
Ogo ni ti wa
A ti ra wa pada
A ti d'omo
Omo ileri
A ti jogun iye
Ainipekun
Ogo ni ti wa
Ohun ta ni O ju wura lo o
Ehn
Ogo ta ni o ju wura lo o
Ehn
Ohun ta ni O ju wura lo o
Ehn
Ogo ta ni o ju wura lo o
Ehn
A ti ra wa pada
A ti d'omo
Omo ileri
A ti jogun iye
Ainipekun
Ogo ni ti wa
A ti ra wa pada
A ti d'omo
Omo ileri
A ti jogun iye
Ainipekun
Ogo ni ti wa
Ko su wa lati ma ko orin
Ti igbani
Ogo f'olorun halleluyah
A le fi igbabo k'orin na
S'oke kikan
Ogo f'Olorun halleluyah
Omo Olorun ni eto
Lati ma bu s'ayo
Pe ona yi nye wa si
Okan wa ns'aferi Re
Nigb'o se a o de afin
Oba wa ologo
Ogo f'olorun
Halleluyah
Owo o le ra
Aiye o le gba lowo wa
Ohun ta ni ju wura lo
Ohun ta ni ju wura lo
Ohun ta ni ju wura lo
Owo o le ra
Aiye o le gba lowo wa
Owo o le ra
Aiye o le gba lowo wa
Ohun ta ni ju wura lo
Ohun ta ni ju wura lo
Ohun ta ni ju wura lo
Owo o le ra
Aiye o le gba lowo wa
Baba mimo lo fi fun wa
Nipa eje Jesu
Ore ofe wa s'aiye
Luli
O ju wura, fadaka
Ohun ta o le na loja ni o
Iyebiye ogo nla ni
E di mu o
Ijo mimo
Owo o le ra
Aiye o le gba lowo wa
Ohun ta ni ju wura lo
Ohun ta ni ju wura lo
Ohun ta ni ju wura lo
Owo o le ra
Aiye o le gba lowo wa
Airopo ibukun
L'eledumare fi fun wa o
Repete repete o repete
Ibukun aitan o repete
Ibukun aiyeraiye
L'eledumare fi fun wa o
Repete repete o repete
Ibukun aitan o repete
Ibukun orun o
L'ore ofe to ga ju lo
Repete repete o repete
Ibukun aitan o repete
Ohun ta fi fun wa
O ju wura lo o
Repete repete o repete
Ibukun aitan o repete
Mo nran yin le ti
Luli yi ju wura lo o
Repete repete o repete
Ibukun aitan o repete
Ohun t'agbe l'Oshoffa lowo
O ju wura lo o
Repete repete o repete
Ibukun aitan o repete
Ohun t'agbe le Bada lowo
O ju wura lo o
Repete repete o repete
Ibukun aitan o repete
Ohun t'agbe le Sanctum lowo
O ju wura lo o
Repete repete o repete
Ibukun aitan o repete
Ogo ijo mimo
O ju wura lo o
Repete, repete o repete
Ibukun aitan o repete
Ohun ta fi fun wa
O ju wura lo o
Repete repete o repete
Ibukun aitan o repete
Ohun ta fi fun wa
O ju wura lo o
Repete repete o repete
Ibukun aitan o repete