Iyin in the Crowd Lyrics
- Genre:Gospel
- Year of Release:2024
Lyrics
Olorun ti mo gb'ojule
Sa ra re ma re
Oba ti mo fi yin fun o
Oba to nse le ri mu se o
Okun pin ya
Agbara re ma ni
O so omi kikoro di adun
Agbara re ma ni
Agan d'olomo
Agbara re ma ni
Odi Jericho wo lu le
Agbara re ma ni
O ku ise Oluwa o seun
Dansaki re Olorun Oba re re
Osuba re rè o
Arugbo Ojo o
Iyin ogo ye o Baba
Iyin ogo ye o Baba