Oluyole Carnival Lyrics
- Genre:Fuji
- Year of Release:2012
Lyrics
Oluyole Carnival - Pasuma
...
Omo garri yi dun gan
Ko de ni sugar rara
Efo yi dun gan
Ko ni fish ooo
E ba n wa ponmo oshi na n pe bayen oo
Omode to ni toun ba dagba oo
Eiyele loun ma n ma je
Ori Eiyele oo wese boy oo koni je Omode o dagba oo