Kegites Special (Orobokibo) Lyrics
- Genre:Fuji
- Year of Release:2012
Lyrics
Kegites Special (Orobokibo) - Pasuma
...
Orobokibo (Kibo leyin, kibo waju kibo)
Orobokibo (Kibo leyin, kibo waju kibo)
Alabi mo d'ode o (Kibo leyin, kibo waju kibo)
Paso mo d'ode o (Kibo leyin, kibo waju kibo)
All round network (Kibo leyin, kibo waju kibo)
Paso mo d'ode o (Kibo leyin, kibo waju kibo)
Orobokibo (Kibo leyin, kibo waju kibo)
Ogun orun sa ni o (Kibo leyin, kibo waju kibo)
Ajebidan ni o (Kibo leyin, kibo waju kibo)
O wulo f'omoge o (Kibo leyin, kibo waju kibo)
Eeeh! (Ayayayaaa)
Ewolewo ewolewo (Eyin paddy mi ewolewo)
Ewolewo ewolewo a (Eyin paddy mi ewolewo)
Eyin t'America ewolewo (Eyin paddy mi ewolewo)
Eyin ti Europe ewolewo (Eyin paddy mi ewolewo)
Yellow sisi le fe ni o abi omo dudu? (Eyin paddy mi ewolewo)
Omo university ewolewo a (Eyin paddy mi ewolewo)
Omo polytechnic ewolewo (Eyin paddy mi ewolewo)
Orobo le fe ni abi lepa? (Eyin paddy mi ewolewo)
Gbogbo omo ile-iwe o ewolewo a (Eyin paddy mi ewolewo)
Firikima, firikima o a jo ma firiki a (Firikima, firikima o a jo ma firiki)
Firikima, firikima o a jo ma firiki o (Firikima, firikima o a jo ma firiki)
If opeke open abuna, I go enter o (Firikima, firikima o a jo ma firiki)
If opeke open abuna, I go se nbe a (Firikima, firikima o a jo ma firiki)
B'olomoge ba fun mi l'aye, emi a dara (Firikima, firikima o a jo ma firiki)
Ehn, odebedebe (Odebe)
Odebedebe (Odebe)
Odebedebe o (Odebe)
Odebedebe (Odebe)
Oyatoyato (Oyato)
Oyatoyato (Oyato)
Ojenbejenbe (Ojenbe)
Ojenbejenbe o (Ojenbe)
Opeke sun m'opaka do obe, obe do
Opeke sun m'opaka do obe, obe do
Opeke sun m'opaka do obe, obe do
Opaka sun m'opeke do obe, obe do
Opeke sun m'opaka do obe, obe do
Odebedebe (Odebe)
Ojenbejenbe (Ojenbe)
Oyatoyato (Oyato)
Oyatoyato (Oyato)
Iyawo gb'omo s'ile tan, o gb'oko s'aya re won ribo desale (Won ribo desale daadaa)
Iyawo gb'omo s'ile tan, o gb'oko s'aya re won ribo desale (Won ribo desale daadaa)